ÌJỌBA TI FI ÒFIN GBÉ ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ ILÉ ÌWÉ IGBINEDION TÍ WỌ́N ṢE AKẸGBẸ́ WỌN MỌ́KUMỌ̀KU.
Lẹ́yìn ìfẹ̀hónúhàn tó gba iwájú ilé ìwé Igbinedion kan ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá, ìjọba ti gba èrò àwọn ajàfẹ́tọ̀ọ́mọnìyàn, àwọn ...







