Hamdiyyah Sharif; ọmọbìnrin tó ké sí gómìnà ìpínlẹ̀ Sokoto pé kí ó wá nǹkan ṣe sí ọ̀rọ̀ àwọn agbésùnmọ̀mí ti di àwátì báyìí. Agbẹjọ́rò rẹ̀; Abba Hikima ló fi ìròyìn yìí léde lórí ìtàkùn ayélujára pé Hamdiyyah lọ ra oúnjẹ ní agbègbè rẹ̀ ní àárọ̀ ọjọ́...
Read moreDetailsArákùnrin kan tí wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní Udochi Amala ti dáná sun ìyàwó àti ọmọ rẹ̀ nítorí pé ó fura pé ìyàwó òun ń yan àlè. Ẹni ogójì ọdún ni Udochi, agbègbè Onicha Ngwa ní ìjọba ìbílẹ̀ Obingwa ni...
Àwọn kan tí wọ́n fura sí pé wọ́n jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn ni wọ́n ti ṣá arákùnrin kan tí wọ́n...
Ilé iṣẹ́ ológun ilẹ̀ yìí, ẹ̀ka àwọn jagunjagun ojú òfurufú ti kéde pé àwọn ti pa ọlọ́wọ́ ọ̀tún Bello Turji...
Ọ̀rọ̀ burúkú tòun tẹ̀rín ni ìròyìn tó tẹ̀ wá lọ́wọ́ láti ìpínlẹ̀ Rivers láàárọ̀ yìí. Ẹni ọdún mẹ́tàlélógójì ni Gift,...
Gómìnà ìpínlẹ̀ Borno; Babangana Zulum ti sọ gudugbẹ ọ̀rọ̀ lónìí nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò tó ṣe...
Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE
We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group