ÀWỌN OBÌNRIN FI Ẹ̀SÙN ÌBÁLÒPỌ̀ KAN PÁSÍTỌ̀ CHRIS OKAFOR.
Pásítọ̀ àgbà ìjọ Mountain of Liberation and Miracle Ministries; Chris Okafor ti gba ìsinmi lẹ́nu iṣẹ́ olúwa fún oṣù kan ...
Pásítọ̀ àgbà ìjọ Mountain of Liberation and Miracle Ministries; Chris Okafor ti gba ìsinmi lẹ́nu iṣẹ́ olúwa fún oṣù kan ...
Àwọn agbésùnmọ̀mí ya wọ abúlé Adanla ní Igbaja, ìjọba ìbílẹ̀ Ifelodun, ìpínlẹ̀ Kwara. Ọjọ́ Ẹtì, ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n ni wọ́n ya ...
Ọwọ́ àwọn ọlọ́pàá ti tẹ obìnrin kan tó gbé ọmọ oṣù méjì tà ní ìpínlẹ̀ Delta. Rita Ughale ni orúkọ ...
Akẹ́kọ̀ọ́ ilé ìwé gíga NOUN kan ti dákẹ́ sínú gbọ̀ngán ìdánwò lásìkò tó ń ṣe ìdánwò lọ́wọ́. Àlàyé tí a ...
Ọwọ́ àwọn ọlọ́pàá ti tẹ obìnrin kan tó ṣètò bí ó ṣe jí ara rẹ̀ gbé pẹ̀lú ọ̀rẹ́ rẹ̀ tó ...
Òṣèrébìnrin ilẹ̀ wa; Tonto Dikeh ti ṣe ìjẹ́rìí sí ọwọ́ Ọlọ́run nínú ayé rẹ̀ nípa bí ó ṣe dẹ́kun mímu ...
Nǹkan bíi aago mẹ́fà àbọ̀ ìdájí ọjọ́rú, ọjọ́ kẹtàdínlógún, oṣù Ọ̀pẹ ni ọkọ̀ àjàgbé eléjò kan pàdánù ìjánu rẹ̀ lójú ...
Àjọ tó ń gbógun ti ayédèrú nǹkan jíjẹ, mímu àti òògùn lílò NAFDAC ti ba àwọn ọjà tó jẹ́ ayédèrú ...
Ladan Zubairu ni ìmáàmù mọ́ṣáláṣí Yusuf Garko tó wà ní Maraba, ìpínlẹ̀ Kano. Ní ìdájí, Ladan yóò pe irun àkọ́kọ́ ...
Ògbóǹtarìgì agbésùnmọ̀mí tó ń da ìpínlẹ̀ Zamfara, Sokoto àti agbègbè láàmú ti jáde sọ̀rọ̀ lórí àwọn ohun gbà-má-bínú tí ìjọba ...
© 2024 -2026 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
We use cookies to improve your experience on our site. By using our site, you consent to cookies.
Manage your cookie preferences below:
Essential cookies enable basic functions and are necessary for the proper function of the website.
These cookies are needed for adding comments on this website.
These cookies are used for managing login functionality on this website.
Statistics cookies collect information anonymously. This information helps us understand how visitors use our website.
Google Analytics is a powerful tool that tracks and analyzes website traffic for informed marketing decisions.
Service URL: policies.google.com (opens in a new window)
Marketing cookies are used to follow visitors to websites. The intention is to show ads that are relevant and engaging to the individual user.
A video-sharing platform for users to upload, view, and share videos across various genres and topics.
Service URL: www.youtube.com (opens in a new window)
© 2024 -2026 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group