Ẹ TẸ̀LÉ MI KÁLỌ INÚ ẸGBẸ́ ÒṢÈLÚ APC TÀBÍ KÍ Ẹ KỌ̀WÉ FIPÒ YÍN SÍLẸ̀ – GÓMÌNÀ ÌPÍNLẸ̀ AKWA IBOM SÍ ÀWỌN KỌMÍṢỌ́NÀ RẸ̀.
Gómìnà ìpínlẹ̀ Akwa Ibom; Umo Eno ti pàṣẹ fún gbogbo àwọn kọmíṣọ́nà rẹ̀ pé kí wọn ó tẹ̀lé òun kálọ ...