• About
  • Advertise
  • Careers
  • Contact
Saturday, June 14, 2025
  • Login
  • Register
No Result
View All Result
NEWSLETTER
ÌWÉ ÌRÒYÌN YORÙBÁ
  • Ilé Wa
  • Ìròyìn
    • All
    • ijamba oko
    • Ìròyìn Agbègbè
    • Ọ̀rọ̀ Ààbò
    • Ọ̀rọ̀ ìdílé
    • Ọrọ̀-Ajé
    • Òṣèlú
    TINUBU NÌKAN LÓ LE SỌ NAÍJÍRÍÀ DỌ̀TUN – TOMPOLO

    ỌWỌ́ ÀWỌN ỌLỌ́PÀÁ AUSTRALIA TẸ ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ TÓ Ń FI ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ ṢÒWÒ.

    ÒJÌLÉNÍGBA-Ó-LÉ-MÉJÌ ÈÈYÀN PÀDÉ IKÚ ÒJIJÌ NÍNÚ ÌJÀMBÁ ỌKỌ̀ BÀLÚÙ.

    ỌKỌ̀ ÀJÀGBÉ AGBÉPO KAN GBANÁ LÓJÚ Ọ̀NÀ MÁROSẸ̀ ÈKÓ SÍ ÌBÀDÀN.

    Ẹ GBÀ WÁ LỌ́WỌ́ ÀWỌN ỌMỌ ẸGBẸ́ ÒKÙNKÙN O – ÀWỌN ARÁ AKWA IBOM

    ALÁGA ÌJỌBA ÌBÍLẸ̀ Ẹ̀PẸ́ FAGI LÉ ÌRUN ỌDÚN ILÉYÁ.

    GBA IṢẸ́ LỌ́WỌ́ ÀWỌN MÍNÍSÍTÀ TÍ WỌN KÒ MỌ IṢẸ́ WỌN NÍṢẸ́ – ORJI KALU SÍ TINUBU

    A TI PA OGÚNLỌ́GỌ̀ ÀWỌN AGBÉSÙNMỌ̀MÍ – ILÉ IṢẸ́ OLÓGUN OJÚ ÒFURUFÚ.

    ILÉ ẸJỌ́ SỌ OLÙKỌ́ TÓ BÁ AKẸ́KỌ̀Ọ́ LÒ PỌ̀ SÍ Ẹ̀WỌ̀N GBÉRE.

  • Ìròyìn Tó Gbòde
  • Eré ìdárayá
  • Ìdánilárayá
    • All
    • Fiimu ati Nollywood
    • Orin
    SAUDI TI KÉDE ỌJỌ́ KẸFÀ, OṢÙ IGBE NÍ ỌJỌ́ ỌDÚN ILÉYÁ.

    ÌGBÉYÀWÓ PRISCILLA MÌLÚ TÌTÌ.

    ÌGBÉYÀWÓ PRISCILLA MÌLÚ TÌTÌ.

    LÁÀRIN TINUBU, EEDRIS ABDULKAREEM ÀTI WOLE SOYINKA.

    Ìròyìn Jákèjádò.

    Ìròyìn Jákèjádò.

    MO TA ILÉ ÀTI Ọ̀NÀ MI LÓRÍ ÀÌSÀN ÌTỌ̀ ṢÚGÀ – AGBÓHÙNSÁFẸ́FẸ́.

    TUFACE RA ÀWỌN AṢỌ TITUN FÚN ÌFẸ́ RẸ̀ TITUN; NATASHA

    ỌKÙNRIN MỌ́KÀNLÉLÓGÚN LÓ BÁ ÌYÀWÓ MI LÒ PỌ̀- ÌJỌBA LANDE

    MI Ò NÍ LE BÁ BABA TEE ṢIṢẸ́ PỌ̀ – ÌJỌBA LANDE.

    ÈMI NI ÌYÀWÓ ẸLẸ́Ẹ̀KEJE ỌKỌ MI :

    ÈMI NI ÌYÀWÓ ẸLẸ́Ẹ̀KEJE ỌKỌ MI :

    Ramadan Kareem!

    Ramadan Kareem!

    • Fiimu ati Nollywood
    • Orin
  • Ìgbé-Ayé
    • All
    • Ìlera
    • Ìrìn Àjò
    • Oge Ṣiṣe

    Ó TI LÉ NÍ ỌGỌ́RÙN-ÚN ÈÈYÀN TÓ TI BÁ ÌṢẸ̀LẸ̀ OMIYALÉ LỌ NÍ ÌPÍNLẸ̀ NIGER.

    A Ń ṢE ÌFILỌ́LẸ̀ ÌPÌLẸ̀ RERE FÚN ỌJỌ́ IWÁJÚ TÓ GÚN RÉGÉ – ÀÀRẸ̀́ BOLA AHMED TINUBU.

    GBỌ̀GÁN ÌDÁNWÓ WÓ PA ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ TARABA.

    ÌYÁ ÀTI ÌYÁ ÌYÁ TA ỌMỌ ỌJỌ́ MÉJÌ.

    Ẹ̀RỌ LỌ ÒṢÌṢẸ́ ILÉ IṢẸ́ KÚNNÁ NÍ ÌPÍNLẸ̀ OGUN.

    Trending Tags

    • Golden Globes
    • Mr. Robot
    • MotoGP 2017
    • Climate Change
    • Flat Earth
    • Oge Sise
    • Ìlera
    • Ìrìn Àjò
  • Fọ́nrán
  • Àṣà Yorùbá
    • All
    • Àjọ̀dún Yorùbá
    • Ìtàn Yorùbá
    • Oríkì
    ÌYÀWÓ NI OLAMIDE FẸ́ FỌ́ IRIN MỌ́ LÓRÍ TÓ FI BA ỌMỌ RẸ̀, ỌMỌ ỌDÚN KAN.

    ILÉ ẸJỌ́ DÁJỌ́ IKÚ FÚN ỌKÙNRIN TÓ ṢEKÚ PA COMFORT JAMES.

    Àwọn agbébọn

    ÀWỌN AGBÉBỌN ṢE ÌKỌLÙ SÍ ÌPÍNLẸ̀ KWARA.

    ÌGBÉYÀWÓ PRISCILLA MÌLÚ TÌTÌ.

    ÌGBÉYÀWÓ PRISCILLA MÌLÚ TÌTÌ.

    ILÉ ỌBA Ọ̀YỌ́ KÒ JÓ ÀMỌ́ A Ó BU ẸWÀ SÍI – ỌBA OWOADE.

    ALÁÀFIN YAN OSUNTOLA NÍ OLÙBÁDÁMỌ̀RÀN PÀTÀKÌ.

    Àkàgbádùn

    Àkàgbádùn

    Ewì

    Ewì.

    • Àjọ̀dún Yorùbá
    • Ìtàn Yorùbá
    • Oríkì
  • Ààyè Olóòtú

Home Ààyè Olóòtú

ỌWỌ́ ÀWỌN ỌLỌ́PÀÁ AUSTRALIA TẸ ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ TÓ Ń FI ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ ṢÒWÒ.

Àti àwọn ìròyìn mìíràn tó gbòde

by Adeola Olanrewaju
June 13, 2025
in Ààyè Olóòtú, Ìròyìn Agbègbè, Ìròyìn òkèrè, Ìròyìn Tó Gbòde, Ọ̀rọ̀ Ààbò, Ọ̀rọ̀ ìdílé, Ọrọ̀-Ajé
0
ỌWỌ́ ÀWỌN ỌLỌ́PÀÁ AUSTRALIA TẸ ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ TÓ Ń FI ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ ṢÒWÒ.
0
SHARES
1
VIEWS
Pín Lórí FacebookPín Lórí ThreadsPín Lórí TwitterPín Lórí Bluesky

Àwọn ọlọ́pàá orílẹ̀-ède Australia ti mú arábìnrin kan tó jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-ède Nàìjíríà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Binta Abubakar lórí ẹ̀sùn pé ó ń fi àwọn ọmọ ṣòwò lábẹ́ ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ tó gbé kalẹ̀.
Ẹni ọdún mẹ́rìndínlọ́gọ́ta ni Binta, òun ni aláṣẹ ilé iṣẹ́ ètò ẹ̀kọ́ kan nílùú Australia tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ BIN Educational Services and Consulting.
Ètò ìwé òfẹ́ ní orílẹ̀-ède Australia ni ilé iṣẹ́ yìí sọ pé òun ń gbé kalẹ̀ àmọ́ níṣe ni wọ́n ń fi àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó bá kó sí wọn lọ́wọ́ ṣiṣẹ́ oko tí Binta sì ń gba owó ọ̀yà wọn sápò.
Ó ti lé ní ọdún méjì tí ìjọba orílẹ̀-ède Australia ti ń tọpinpin Binta kí wọ́n tó wá he é bí ìgbín lánàá; Ọjọ́rú, ọjọ́ kejìlá, oṣù Okúdù ní pápákọ̀ òfurufú Brisbane.
Ẹ̀sùn tí ìjọba Australia fi kan Binta ni pé ó ń fi ètò ẹ̀kọ́ òfẹ́ tan àwọn akẹ́kọ̀ọ́ láti orílẹ̀-ède Guinea níbi tó tẹ̀dó sí wá sí orílẹ̀-ède Australia, lọ́gán tí àwọn ọmọ náà bá balẹ̀ sí Australia ni yóò kó wọn lọ sí Queensland níbi tí wọn yóò ti fipá tọwọ́ bọ àwọn ìwé àdéhùn pé àwọn jẹ Binta ní owó ìrìnnà wá sí Australia àwọn sì ṣetán àti ṣiṣẹ́ sìn ín.
Lẹ́yìn náà ni yóò kó wọn lọ sí oko èso níbi tí wọn yóò ti máa ṣiṣẹ́ fún wákàtí mẹ́wàá lójúmọ́. Èyíkéyìí nínú àwọn ọmọ náà tó bá kọ̀ láti ṣiṣẹ́, Binta yóò halẹ̀ mọ́ ọn pé òun yóò fi ẹjọ́ rẹ̀ sun àwọn ọlọ́pàá tàbí kí ó dúnkokò mọ́ àwọn ẹbí rẹ̀ nílé.
Ìjọba Australia wí pé ó ti lé ní àwọn ọmọ mẹ́ẹ̀dógún tó ti kó sí ọwọ́ Binta láàrín oṣù Agẹmọ ọdún 2024 sí àsìkò yìí.
Bákan náà ni wọ́n sọ pé ilé iṣẹ́ tó ni àwọn oko náà kò mọ̀ sí ohun tí Binta ń fi àwọn ọmọ náà ṣe yìí, òun kàn ń san owó ọ̀yà wọn fún ọ̀gá wọn ni.
Èsùn oníkókó mọ́kànlélọ́gbọ̀n ni ìjọba Australia fi kan Binta wọ́n sì ti gba onídùúró Binta báyìí yóò sì fi ojú ba ilé ẹjọ́ ní ọjọ́ kọkàndínlógún, oṣù Òwẹ̀wẹ̀, ọdún yìí.

Ìròyìn mìíràn tó tún mi ìlú tìtì ni ìròyìn ìjàm̀bá ọkọ̀ ojú òfurufú tó gbéra ní orílẹ̀-ède India tó sì já lulẹ̀. Ìròyìn náà kà báyìí pé:

Orílẹ̀-èdè India kan lọ́jọ́ kejìlá, oṣù Okúdù nígbà tí ọkọ̀ bàlúù kan tó kó èrò tó lé ní igba já lulẹ̀ tó sì gbaná lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.
Pápákọ̀ òfurufú tó wà ní Ahmedabad ni ọkọ̀ yìí ti gbéra, London ni ó ń lọ àmọ́ kò tó ìṣẹ́jú kan lẹ́yìn tó gbéra ló já lu ilé àwọn dọ́kítà pápákọ̀ òfurufú náà.
Èèyàn kan ṣoṣo ló jáde nínú rẹ̀ láàyè àmọ́ pẹ̀lú àpá ni.
Ìròyìn fi yé wa pé ìjayà ló sẹkú pa ọ̀pọ̀ àwọn èrò náà kó tó di pé ó já gan-an.
Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè káàkiri ni wọ́n ń kí India kú ilédè àwọn èèyàn tó bá ìṣẹlẹ náà rìn.

Ní orílẹ̀-ède wa Nàìjíríà:
Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti dá ẹ̀wọ̀n oṣù mẹta lórí ẹ̀sùn pé ó kojú ẹ̀ṣọ́ aláàbò ojú pópó.
Ìròyìn fi yé wa pé Morufudeen Idowu jẹ́ ẹni ọdún méjìléláàdọ́ta, ó ṣẹ̀ṣẹ̀ dé láti orílẹ̀-èdè Canada ni. Lọ́jọ́ tí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ṣẹ̀, Morufudeen fẹ́ sọdá títì ní Ọjọ́ta nígbà tí àwọn ẹ̀ṣọ́ aláàbò dáa dúró tí wọ́n sì fẹ́ mú un pé ó ti ṣẹ̀ sí òfin.
Morufudeen kò gbà fún àwọn ẹ̀ṣọ́ aláàbò KAI yìí, ó bá wọn ná an tán bíi owó ní èyí tó já sí kí wọn ó gbéná wojú ara wọn.
Ní báyìí, ilé ẹjọ́ tó fìkàlẹ̀ sí Èkó ti pàṣẹ kí Morufudeen ó lọ lo oṣù mẹ́ta lọ́gbà ẹ̀wọ̀n fún kíkojú òṣìṣẹ́ ìjọba.
Kọ́míṣọ́nà fún ètò àyíká àti àwọn ohun àlùmọ́nì inú omi ìpínlẹ̀ Èkó; Tokunbo Wahab ló fi ìròyìn yìí sí ojú òpó X rẹ̀.

Ní ìpínlẹ̀ Ogun:

Nínú fọ́nrán kan tó gbòde kan ni a ti rí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ìwé gíga ìmọ̀ ẹ̀rọ, Igbesa ní ìpínlẹ̀ Ogun tí wọ́n de akẹgbẹ́ wọn lóbìnrin mọ́lẹ̀, wọ́n so ọwọ́ rẹ̀ méjèèjì wọ́n sì ń nà án ní ẹgba.
Ẹ̀sùn tí wọ́n fi kan ọmọbìnrin yìí náà ni pé ó gba ọ̀rẹ́kùnrin ọ̀kan nínú wọn.
Wọ́n na ọmọbìnrin yìí tóbẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́ tí ẹjẹ̀ fi dà lára rẹ̀ tó sì ní àpá lẹ́yìn.
Wọ́n sọ nínú fọ́nrán náà pé ìyá àwọn mọ̀ nípa ohun tí àwọn ṣe yìí, ẹni tó bá mọ̀ ni kó lọ fi ẹjọ́ sùn, wọ́n sọ pẹ̀lú ìgboyà pé kò sí ohun tí yóò ṣẹlẹ̀.
Ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ogun fèsì fún àwọn akọ̀ròyìn pé àwọn ọlọ́pàá Igbesa ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ lórí rẹ̀.

Ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàm̀bá ọkọ̀ àjàgbé agbépo:
Ìpayà bá àwọn arìnrìnàjò lójú ọ̀nà márosẹ̀ Ọ̀yọ́ sí Ògbómọ̀ṣọ́ lánàá nígbà tí ọkọ̀ àjàgbé agbépo kan pàdánù ìjánu rẹ̀ tó sì ṣubú lulẹ̀.
Kíá ni gbogbo àwọn èrò ti bọ́ sílẹ̀ nínú ọkọ̀ wọn tí wọ́n sì sá sí abẹ́ igi kan tí kò jìnà púpọ̀ ní ìrètí ìgbà tí àwọn panápaná yóò dé.
Oríta Irepo ni èyí ti ṣẹlẹ̀, àwọn tí ó ṣe ojú wọn ṣe àlàyé fún àwọn akọ̀ròyìn pé ọkọ̀ àjàgbé agbépo náà pàdánù ìjánu rẹ̀ lójijì ó sì ń sáré lọ, àwọn ọlọ́kọ̀ yára dá ọkọ̀ wọn dúró kí àwọn èrò ó le sọ̀ kalẹ̀ kí ó tó di pé ọkọ̀ náà fi ẹgbẹ́ lélẹ̀.
Kò sí ẹni tó fara pa tàbí bá ìṣẹ̀lẹ̀ yìí lọ ibi súnkẹrẹ fàkẹrẹ ọkọ̀ ló mọ.

Àwọn arìnrìnàjò yóò tẹ̀síwájú lẹ́yìn tí àwọn panápaná bá gba agbára lọ́wọ́ àgbá epo náà.

Facebook Comments Box
Tags: #iweiroyinyoruba#ìwéròyìnyorùbá #NewsOnline#newsfeed#newsupdates#osunstateÌròyìn Tó Gbòdenewsupdatetrending
Adeola Olanrewaju

Adeola Olanrewaju

Next Post
TINUBU NÌKAN LÓ LE SỌ NAÍJÍRÍÀ DỌ̀TUN – TOMPOLO

TINUBU NÌKAN LÓ LE SỌ NAÍJÍRÍÀ DỌ̀TUN – TOMPOLO

Discussion about this post

Recommended

Babajide Sanwoolu

ÌJỌBA ÈKÓ KÉDE OWÓ ÌTANRÀN TITUN FÚN ÀWỌN AWAKỌ̀.

4 months ago
INÁ ỌMỌ Ọ̀RARA NÍ ÌPÍNLẸ̀ RIVERS

INÁ ỌMỌ Ọ̀RARA NÍ ÌPÍNLẸ̀ RIVERS

3 months ago

Popular News

  • ỌWỌ́ ÀWỌN ỌLỌ́PÀÁ AUSTRALIA TẸ ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ TÓ Ń FI ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ ṢÒWÒ.

    ỌWỌ́ ÀWỌN ỌLỌ́PÀÁ AUSTRALIA TẸ ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ TÓ Ń FI ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ ṢÒWÒ.

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • TINUBU NÌKAN LÓ LE SỌ NAÍJÍRÍÀ DỌ̀TUN – TOMPOLO

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • ÒJÌLÉNÍGBA-Ó-LÉ-MÉJÌ ÈÈYÀN PÀDÉ IKÚ ÒJIJÌ NÍNÚ ÌJÀMBÁ ỌKỌ̀ BÀLÚÙ.

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • ỌKỌ̀ ÀJÀGBÉ AGBÉPO KAN GBANÁ LÓJÚ Ọ̀NÀ MÁROSẸ̀ ÈKÓ SÍ ÌBÀDÀN.

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • Ẹ GBÀ WÁ LỌ́WỌ́ ÀWỌN ỌMỌ ẸGBẸ́ ÒKÙNKÙN O – ÀWỌN ARÁ AKWA IBOM

    0 shares
    Share 0 Tweet 0

Connect with us

Newsletter

Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE

Category

Site Links

  • Register
  • Log in
  • Entries feed
  • Comments feed
  • WordPress.org

About Us

We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.

  • About
  • Advertise
  • Careers
  • Contact

© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group

Welcome Back!

Sign In with Facebook
Sign In with Google
Sign In with Linked In
OR

Login to your account below

Forgotten Password? Sign Up

Create New Account!

Sign Up with Facebook
Sign Up with Google
Sign Up with Linked In
OR

Fill the forms below to register

All fields are required. Log In

Retrieve your password

Please enter your username or email address to reset your password.

Log In