• About
  • Advertise
  • Careers
  • Contact
Saturday, June 14, 2025
  • Login
  • Register
No Result
View All Result
NEWSLETTER
ÌWÉ ÌRÒYÌN YORÙBÁ
  • Ilé Wa
  • Ìròyìn
    • All
    • ijamba oko
    • Ìròyìn Agbègbè
    • Ọ̀rọ̀ Ààbò
    • Ọ̀rọ̀ ìdílé
    • Ọrọ̀-Ajé
    • Òṣèlú
    TINUBU NÌKAN LÓ LE SỌ NAÍJÍRÍÀ DỌ̀TUN – TOMPOLO

    TINUBU NÌKAN LÓ LE SỌ NAÍJÍRÍÀ DỌ̀TUN – TOMPOLO

    ỌWỌ́ ÀWỌN ỌLỌ́PÀÁ AUSTRALIA TẸ ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ TÓ Ń FI ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ ṢÒWÒ.

    ỌWỌ́ ÀWỌN ỌLỌ́PÀÁ AUSTRALIA TẸ ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ TÓ Ń FI ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ ṢÒWÒ.

    ÒJÌLÉNÍGBA-Ó-LÉ-MÉJÌ ÈÈYÀN PÀDÉ IKÚ ÒJIJÌ NÍNÚ ÌJÀMBÁ ỌKỌ̀ BÀLÚÙ.

    ÒJÌLÉNÍGBA-Ó-LÉ-MÉJÌ ÈÈYÀN PÀDÉ IKÚ ÒJIJÌ NÍNÚ ÌJÀMBÁ ỌKỌ̀ BÀLÚÙ.

    ỌKỌ̀ ÀJÀGBÉ AGBÉPO KAN GBANÁ LÓJÚ Ọ̀NÀ MÁROSẸ̀ ÈKÓ SÍ ÌBÀDÀN.

    ỌKỌ̀ ÀJÀGBÉ AGBÉPO KAN GBANÁ LÓJÚ Ọ̀NÀ MÁROSẸ̀ ÈKÓ SÍ ÌBÀDÀN.

    Ẹ GBÀ WÁ LỌ́WỌ́ ÀWỌN ỌMỌ ẸGBẸ́ ÒKÙNKÙN O – ÀWỌN ARÁ AKWA IBOM

    Ẹ GBÀ WÁ LỌ́WỌ́ ÀWỌN ỌMỌ ẸGBẸ́ ÒKÙNKÙN O – ÀWỌN ARÁ AKWA IBOM

    ALÁGA ÌJỌBA ÌBÍLẸ̀ Ẹ̀PẸ́ FAGI LÉ ÌRUN ỌDÚN ILÉYÁ.

    ALÁGA ÌJỌBA ÌBÍLẸ̀ Ẹ̀PẸ́ FAGI LÉ ÌRUN ỌDÚN ILÉYÁ.

    GBA IṢẸ́ LỌ́WỌ́ ÀWỌN MÍNÍSÍTÀ TÍ WỌN KÒ MỌ IṢẸ́ WỌN NÍṢẸ́ – ORJI KALU SÍ TINUBU

    GBA IṢẸ́ LỌ́WỌ́ ÀWỌN MÍNÍSÍTÀ TÍ WỌN KÒ MỌ IṢẸ́ WỌN NÍṢẸ́ – ORJI KALU SÍ TINUBU

    A TI PA OGÚNLỌ́GỌ̀ ÀWỌN AGBÉSÙNMỌ̀MÍ – ILÉ IṢẸ́ OLÓGUN OJÚ ÒFURUFÚ.

    A TI PA OGÚNLỌ́GỌ̀ ÀWỌN AGBÉSÙNMỌ̀MÍ – ILÉ IṢẸ́ OLÓGUN OJÚ ÒFURUFÚ.

    ILÉ ẸJỌ́ SỌ OLÙKỌ́ TÓ BÁ AKẸ́KỌ̀Ọ́ LÒ PỌ̀ SÍ Ẹ̀WỌ̀N GBÉRE.

    ILÉ ẸJỌ́ SỌ OLÙKỌ́ TÓ BÁ AKẸ́KỌ̀Ọ́ LÒ PỌ̀ SÍ Ẹ̀WỌ̀N GBÉRE.

    • Ìròyìn Agbègbè
    • Ọ̀rọ̀ Ààbò
    • Ọrọ̀-Ajé
    • Òṣèlú
  • Ìròyìn Tó Gbòde
  • Eré ìdárayá
  • Ìdánilárayá
    • All
    • Fiimu ati Nollywood
    • Orin
    SAUDI TI KÉDE ỌJỌ́ KẸFÀ, OṢÙ IGBE NÍ ỌJỌ́ ỌDÚN ILÉYÁ.

    SAUDI TI KÉDE ỌJỌ́ KẸFÀ, OṢÙ IGBE NÍ ỌJỌ́ ỌDÚN ILÉYÁ.

    ÌGBÉYÀWÓ PRISCILLA MÌLÚ TÌTÌ.

    ÌGBÉYÀWÓ PRISCILLA MÌLÚ TÌTÌ.

    LÁÀRIN TINUBU, EEDRIS ABDULKAREEM ÀTI WOLE SOYINKA.

    LÁÀRIN TINUBU, EEDRIS ABDULKAREEM ÀTI WOLE SOYINKA.

    Ìròyìn Jákèjádò.

    Ìròyìn Jákèjádò.

    MO TA ILÉ ÀTI Ọ̀NÀ MI LÓRÍ ÀÌSÀN ÌTỌ̀ ṢÚGÀ – AGBÓHÙNSÁFẸ́FẸ́.

    MO TA ILÉ ÀTI Ọ̀NÀ MI LÓRÍ ÀÌSÀN ÌTỌ̀ ṢÚGÀ – AGBÓHÙNSÁFẸ́FẸ́.

    TUFACE RA ÀWỌN AṢỌ TITUN FÚN ÌFẸ́ RẸ̀ TITUN; NATASHA

    TUFACE RA ÀWỌN AṢỌ TITUN FÚN ÌFẸ́ RẸ̀ TITUN; NATASHA

    ỌKÙNRIN MỌ́KÀNLÉLÓGÚN LÓ BÁ ÌYÀWÓ MI LÒ PỌ̀- ÌJỌBA LANDE

    MI Ò NÍ LE BÁ BABA TEE ṢIṢẸ́ PỌ̀ – ÌJỌBA LANDE.

    ÈMI NI ÌYÀWÓ ẸLẸ́Ẹ̀KEJE ỌKỌ MI :

    ÈMI NI ÌYÀWÓ ẸLẸ́Ẹ̀KEJE ỌKỌ MI :

    Ramadan Kareem!

    Ramadan Kareem!

    • Fiimu ati Nollywood
    • Orin
  • Ìgbé-Ayé
    • All
    • Ìlera
    • Ìrìn Àjò
    • Oge Ṣiṣe

    Ó TI LÉ NÍ ỌGỌ́RÙN-ÚN ÈÈYÀN TÓ TI BÁ ÌṢẸ̀LẸ̀ OMIYALÉ LỌ NÍ ÌPÍNLẸ̀ NIGER.

    Ó TI LÉ NÍ ỌGỌ́RÙN-ÚN ÈÈYÀN TÓ TI BÁ ÌṢẸ̀LẸ̀ OMIYALÉ LỌ NÍ ÌPÍNLẸ̀ NIGER.

    A Ń ṢE ÌFILỌ́LẸ̀ ÌPÌLẸ̀ RERE FÚN ỌJỌ́ IWÁJÚ TÓ GÚN RÉGÉ – ÀÀRẸ̀́ BOLA AHMED TINUBU.

    GBỌ̀GÁN ÌDÁNWÓ WÓ PA ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ TARABA.

    A Ń ṢE ÌFILỌ́LẸ̀ ÌPÌLẸ̀ RERE FÚN ỌJỌ́ IWÁJÚ TÓ GÚN RÉGÉ – ÀÀRẸ̀́ BOLA AHMED TINUBU.

    A Ń ṢE ÌFILỌ́LẸ̀ ÌPÌLẸ̀ RERE FÚN ỌJỌ́ IWÁJÚ TÓ GÚN RÉGÉ – ÀÀRẸ̀́ BOLA AHMED TINUBU.

    ÌYÁ ÀTI ÌYÁ ÌYÁ TA ỌMỌ ỌJỌ́ MÉJÌ.

    Ẹ̀RỌ LỌ ÒṢÌṢẸ́ ILÉ IṢẸ́ KÚNNÁ NÍ ÌPÍNLẸ̀ OGUN.

    Trending Tags

    • Golden Globes
    • Mr. Robot
    • MotoGP 2017
    • Climate Change
    • Flat Earth
    • Oge Sise
    • Ìlera
    • Ìrìn Àjò
  • Fọ́nrán
  • Àṣà Yorùbá
    • All
    • Àjọ̀dún Yorùbá
    • Ìtàn Yorùbá
    • Oríkì
    ÌYÀWÓ NI OLAMIDE FẸ́ FỌ́ IRIN MỌ́ LÓRÍ TÓ FI BA ỌMỌ RẸ̀, ỌMỌ ỌDÚN KAN.

    ILÉ ẸJỌ́ DÁJỌ́ IKÚ FÚN ỌKÙNRIN TÓ ṢEKÚ PA COMFORT JAMES.

    Àwọn agbébọn

    ÀWỌN AGBÉBỌN ṢE ÌKỌLÙ SÍ ÌPÍNLẸ̀ KWARA.

    ÌGBÉYÀWÓ PRISCILLA MÌLÚ TÌTÌ.

    ÌGBÉYÀWÓ PRISCILLA MÌLÚ TÌTÌ.

    ILÉ ỌBA Ọ̀YỌ́ KÒ JÓ ÀMỌ́ A Ó BU ẸWÀ SÍI – ỌBA OWOADE.

    ALÁÀFIN YAN OSUNTOLA NÍ OLÙBÁDÁMỌ̀RÀN PÀTÀKÌ.

    ILÉ ỌBA Ọ̀YỌ́ KÒ JÓ ÀMỌ́ A Ó BU ẸWÀ SÍI – ỌBA OWOADE.

    ILÉ ỌBA Ọ̀YỌ́ KÒ JÓ ÀMỌ́ A Ó BU ẸWÀ SÍI – ỌBA OWOADE.

    Ìròyìn Jákèjádò.

    Ìròyìn Jákèjádò.

    Àkàgbádùn

    Àkàgbádùn

    Ewì

    Ewì.

    • Àjọ̀dún Yorùbá
    • Ìtàn Yorùbá
    • Oríkì
  • Ààyè Olóòtú

Home Ààyè Olóòtú

NATASHA TỌRỌ ÀFORÍJÌ Ẹ̀DẸ LỌ́WỌ́ AKPABIO LÓRÍ Ẹ̀SÙN TÓ FI KÀN ÁN.

Wọ́n ní ẹ̀bẹ̀ làá bẹ òṣìkà ni Natasha fi lẹ́tà náà ṣe.

by Adeola Olanrewaju
April 28, 2025
in Ààyè Olóòtú, Ìgbé-Ayé, Ìròyìn, Ìròyìn Tó Gbòde, Òṣèlú
0
ARABÌNRIN KEMI KÚ TOYÚNTOYÚN NÍTORÍ KÒ NÍ ẸGBẸ̀RÚN LỌ́NÀ Ẹ̀Ẹ́DẸ́GBẸ̀TA NÁÍRÀ.
0
SHARES
12
VIEWS
Pín Lórí FacebookPín Lórí ThreadsPín Lórí TwitterPín Lórí Bluesky

Natasha Akpoti-Uduaghan; ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ilẹ̀ yìí ti kọ lẹ́tà ìtọrọ àforíjì sí olórí ilé ìgbìmọ̀ àṣòfin ilẹ̀ yìí; Godswill Akpabio lórí ẹ̀sùn tó fi kàn-án. Àkóónú lẹ́tà náà fi hàn pé kò ti inú rẹ̀ wá, ó kàn fẹ́ mú òfin ṣẹ ni.
Lẹ́tà náà kà báyìí pé:
Sí olórí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin, ẹni àpónlé Godswill Akpabio, mo kọ ìwé ìtọrọ àforíjì yìí pẹ̀lú àbámọ̀ pé mo ṣe ara mi lẹ́ni àpónlé àti ẹni iyì níwájú ìrẹ ọlọ́lájùlọ.
Mo ti ro ohun tí mo ṣe yìí wò bíi ohun tí kò yẹ kó ní àforíjì nípa pé mo kọ̀ láti gbà pé ṣíṣe àṣeyọrí láwọn apá ibìkan kìí ṣe nípa kíkún ojú òṣùwọ̀n bíkòṣe nípa ṣíṣe ohun tí adarí bá fẹ́ kò báà jẹ́ ohun tímọ́tímọ́.
Ó burú pé mi ò tẹ́ ìfẹ́ inú rẹ nítorí mi ò mọ̀ pé ẹ̀tọ́ rẹ̀ ni nínú ìwé òfin rẹ tí kò lákọsílẹ̀. Lóòótọ́, ó yẹ kí n tọrọ àforíjì lọ́wọ́ rẹ fún mímú iṣẹ́ mi lọ́kùnńkúndùn ju ìbálopọ̀ lọ àti fún mímú iṣẹ́ ìlú lọ́kùnńkúndùn ju afẹ́ lọ.
Mo ti rí ipa tí ìṣesí mi yìí ní; àwọn ipa bíi fífi iṣẹ́ aṣòfin falẹ̀ àti inú bíbí, fún ìdí èyí mo tẹ orí mi ba pẹ̀lú ìtìjú inú ìwé ìtàn.
Dákun wá ibi tó dáa nínú ọkàn rẹ láti ṣe àforíjì fún obìnrin alágídí yìí tó rò pé ìbò àwọn aráàlú ló gbé òun dépò láìmọ̀ pé ìdí lòun fi dépò.
Èmi ni tìrẹ tòótọ́ láláìní tẹ́fẹ̀ẹ́ inú rẹ, Natasha H Akpoti Uduaghan. Kò bẹ̀rù, kò ṣeé fowó rà, kò ṣeé ṣẹ́.

Ẹ̀sùn tó fi kan Akpabio náà ni pé ó fẹ́ bá òun lájọsepọ̀, àìgbà fún un ló fàá tó fi ń fìyà jẹ òun nílé ìgbìmọ̀.
Ọ̀rọ̀ yìí ti dá ọ̀pọ̀lọpọ̀ awuyewuye sílẹ̀ láti ìgbà tó ti bẹ̀rẹ̀, Akpabio dá Natasha dúró lórí ẹ̀sùn yìí, Natasha náà ò sì gbà lẹ́rọ̀. Ó gbé ẹjọ́ lọ sí ọ̀dọ àwọn àjọ òkèrè àti àgbáyé. Onírúurú òfin ni ilé ẹjọ́ ti fi de Natasha àti Akpabio, wọ́n ní wọn kò gbọdọ̀ bá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ lórí rẹ̀ mọ́ títí ìgbẹ́jọ́ yóò fi parí, òfin yìí kò yọ àwọn agbẹjọrò wọn sílẹ̀.
A kò gbọ́ nǹkankan mọ́ lórí rẹ̀ títí di ìgbà tí Natasha fi kọ lẹ́tà ẹ̀bẹ̀ ‘Jẹ n ráyé gbé’ yìí. Èsì tí Akpabio yóò fọ̀ ni a ń retí báyìí.
Nígbà tí a ń retí èsì Akpabio, ẹ jẹ́ ká bojú wẹ̀yìn, ká wo bí okùn ọ̀rọ̀ náà ṣe gùn wá gan-an.
Natasha Akpoti-Uduaghan ni ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ilẹ̀ yìí tó ń ṣojú ẹ̀kun àárín gbùngbùn Kogi, nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan tó ṣe pẹ̀lú ilé iṣẹ́ amóhùnmáwòrán ló ti tú pẹrẹpẹ́ẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀.
Natasha wí pé olórí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ìyẹn Godswill Akpabio ń fòró òun nílé ìgbìmọ̀ nítorí pé òun kò gbà kò báa ní àjọṣepọ̀.
Natasha ṣe àlàyé pé gbogbo ọ̀rọ̀ náà bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 2023 nígbà tí Akpabio pe òun sì àpèjẹ ọjọ́ ìbí nínú ilé rẹ̀.
Natasha wí pé òun àti ọkọ òun ni àwọn jọ lọ sí ìbi àpèjẹ náà, lẹ́yìn tí ó kí ọkọ òun tán, Akpabio di òun lọ́wọ́ mú ó sì wí pé òun fẹ́ fi àyíká ilé náà han òun.
Gẹ́gẹ́ bíi àlàyé tí Natasha ṣe, Akpabio mú Natasha kúrò ní iwájú ọkọ rẹ̀ lọ sí yàrá ìgbàlejò kan nínú ilé náà, nígbà tí wọ́n jókòó tán, Akpabio béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé ṣé ó fẹ́ràn ilé náà, Natasha fèsì pé ilé náà dára gan-an ni.
Ohun tí Akpabio wá wí ni pé ‘Ní báyìí tí o ti di ọmọ ilé ìgbìmọ̀, wàá wá ààyè máa wá síbi ká jọ máa gbádùn ara wa, wàá dẹ̀ gbádùn ẹ̀ gan-an’
Lẹ́yìn ìgbà náà ni òun ríi pé àwọn wọ́n yọ ìwé tí òun kọ nípa ilé iṣẹ́ irin Ajaokuta sẹ́yìn lẹ́ẹ̀marùn-ún ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀, nígbà tí òun sì lọ bá olórí ilé ìgbìmọ̀ ìyẹn Akpabio, ohun tó sọ fún òun ni pé ‘ Natasha, èmi ni olórí ilé, bí o bá tọ́jú mi tóo mu inú mi dùn, yùngbà bí èèrà inú ṣúgà lóó máa gbádùn’
Natasha wí pé òun ṣebí ẹni tí kò gbọ́ ohun tó sọ. Natasha ṣe àpèjúwe ọ̀rọ̀ náà bíi ti olùkọ́ tó ń fi ìyà jẹ akẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ nítorí ó kọ̀ láti báa lájọṣepọ̀.
Ohun tó wá fa gbogbo yánpọnyánrin yìí gan-an ni èdè àìyedè tó ṣẹlẹ̀ láàrin Natasha àti Akpabio níbi ìjókòó ilé nígbà tí Akpabio pààrọ̀ ààyè rẹ̀ láìsọ fún un tẹ́lẹ̀.
Àwọn ẹ̀ṣọ́ tí wọ́n kó ìbọn lọ́wọ́ ló dínà mọ́ ọn nígbà tí ó fẹ́ lọ sí ààyè rẹ̀ lọ jókòó, wọ́n wí fún un pé Akpabio ti pààrọ̀ ìjokòó rẹ̀ kò sí ní anfààní láti jókòó sí ibẹ̀ yẹn mọ́.
Ohun tó bí Natasha nínú ni pé Akpabio kò sọ fún un tẹ́lẹ̀ pé òun ti pààrọ̀ ààyè rẹ̀, kódà, òun wá sí ìjokòó tó kọjá òun sì jókòó sí ààyè òun.
Natasha tẹ̀síwájú nínú àlàyé rẹ̀ pé àwọn akẹgbẹ́ òun wí fún òun pé kí òun ó má béèrè nítorí pé ẹ̀dẹ ni.
Ọ̀rọ̀ yìí ti bí ọ̀pọlọpọ̀ awuyewuye láàrin àwọn olóṣèlú àti lórí ìkànnì ayélujára.
Igbákejì ààrẹ ìjarùn-ún; Atiku Abubakar ganu sí ọ̀rọ̀ náà, ó wí pé kí wọn ó ṣe ìwádìí tó jinlẹ̀ lórí ẹ̀sùn tí Natasha fi kan Akpabio yìí.
Ọ̀ṣẹ̀ méjì ni wọ́n fún ìgbìmọ̀ tó ń ṣe ìwádìí ọ̀rọ̀ náà láti jábọ̀ fún gbogbo ilé.
Ìwádìí kò tíì parí tí Akpabio fi kọ ọ́ sójú òpó ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ Facebook rẹ̀ pé ‘Ṣé Natasha rò pé ẹ̀tọ́ òun ni ipò aṣòfin ni? Lẹ́ni tí kò mọ̀ ju kó máa kun ojú kó sì máa wọ aṣọ tó fara sílẹ̀ wá sí ìjokòó ilé’
Ohun tí Akpabio kọ yìí ni agbẹjọ́rò Natasha fi pe ẹjọ́ mìíràn tó sì béèrè fún ọgọ́rùn-ún bílíọ̀nù owó ìtanràn.
Èyí ni wọ́n ń fà lọ́wọ́ tí ìyàwó Akpabio fi jáde wá gbẹ̀rí ọkọ rẹ̀ jẹ́.
Arábìnrin Ekaette Akpabio; Aya Godswill Akpabio pe Natasha lẹ́jọ́ fún ìbanilórúkọjẹ́. Ó wí pé ọkọ òun olówó orí òun jẹ́ ẹni tó kóra rẹ̀ ní ìjánu, ó wí pé Akpabio kò le kọnu sí Natasha débi pé yóò tún ní kó máa wá sí ilé àwọn. Ekaette wí pé kí Natasha ó ki ọwọ́ ọmọ rẹ̀ bọ aṣọ nítorí pé ọkọ òun kò le ṣe irú rẹ̀.
Arábìnrin Ekaette Akpabio kò ṣàì má mẹ́nu ba pé ọkọ òun; Godswill Akpabio ti fi ìgbà kan jẹ́ Gómìnà ìpínlẹ̀ Akwa-Ibom, ó wí pé àwọn obìnrin tí wọ́n dára ju Natasha lọ wà nínú ìgbìmọ̀ rẹ̀ kò sì sí èyí tó sọ pé ọkọ òun kọnu sí òun rí. Bílíọ̀nù ọ̀tàlérúgba-ó-dín-mẹ́wàá náírà ni Ekaette bèèrè fún bíi owó ìtanràn lọ́wọ́ Natasha.
Oríṣìí àwọn èèyàn, ikọ̀ àti lájọlájọ ló ti dìde sí ọ̀rọ̀ yìí. Gbogbo wọn ló bèèrè fún ìwádìí tó jinlẹ̀ lórí ẹ̀sùn tí Natasha fi kan Akpabio yìí.
Wọ́n ní àwọn obìnrin máa ń kojú àwọn nǹkan báyìí ní àwùjọ ní èyí tó máa ń mú ìfàsẹ́yìn bá wọn làtàrí àwọn ọ̀gá tàbí olóríkórí báyìí, wọ́n ní àwọn ń retí èsì tó yanrantí láti ìgbìmọ̀ tó ń ṣe ìwádìí náà.
Nínú ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin —
Àwọn obìnrin mẹ́ta yòókù wí pé ó lòdì sí òfin ilé kí àwọn ó tú ìdí ara àwọn síta, nítorí náà, àwọn kò ní le wí nǹkankan nípa Natasha. Àmọ́, ọ̀kan nínú wọn wí pé kìí ṣe obìnrin nìkan ni wọ́n máa ń pa ìjokòó rẹ̀ dà nínú ilé àmọ́ obìnrin ló máa ń ṣẹlẹ̀ sí jù.
Àwọn ọkùnrin ilé gbè lẹ́yìn Akpabio, ọ̀kan nínú àwọn wí pé irọ́ funfun balau ni Natasha ń pa pé nítorí Akpabio pa ìjokòó rẹ̀ dà ló ṣe pa adúrú irọ́ bàǹtàbanta yẹn mọ́ ọn.

Ní báyìí, Natasha ti kọ ìwé ìtọrọ àforíjì lórí ẹ̀sùn tó fi kàn án, ẹ jẹ́ á jọ máa retí èsì tì Akpabio yóò fọ̀.

Facebook Comments Box
Tags: #iweiroyinyoruba#ìwéròyìnyorùbá #NewsOnline#newsfeed#newsupdatesbreaking newsÌròyìnIwe Iroyin Yorubanewsupdatepoliticstrending
Adeola Olanrewaju

Adeola Olanrewaju

Next Post
Àwọn agbébọn

ÈÈYÀN MẸ́TÀDÍNLÓGÚN NI ÀWỌN AGBÉSÙNMỌ̀MÍ PA NÍ ADAMAWA.

Recommended

Ìròyìn Jákèjádò.

Ìròyìn Jákèjádò.

4 months ago
Ìròyìn Jákèjádò.

Ìròyìn Jákèjádò.

3 months ago

Popular News

  • ỌWỌ́ ÀWỌN ỌLỌ́PÀÁ AUSTRALIA TẸ ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ TÓ Ń FI ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ ṢÒWÒ.

    ỌWỌ́ ÀWỌN ỌLỌ́PÀÁ AUSTRALIA TẸ ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ TÓ Ń FI ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ ṢÒWÒ.

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • TINUBU NÌKAN LÓ LE SỌ NAÍJÍRÍÀ DỌ̀TUN – TOMPOLO

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • ÒJÌLÉNÍGBA-Ó-LÉ-MÉJÌ ÈÈYÀN PÀDÉ IKÚ ÒJIJÌ NÍNÚ ÌJÀMBÁ ỌKỌ̀ BÀLÚÙ.

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • ỌKỌ̀ ÀJÀGBÉ AGBÉPO KAN GBANÁ LÓJÚ Ọ̀NÀ MÁROSẸ̀ ÈKÓ SÍ ÌBÀDÀN.

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • Ẹ GBÀ WÁ LỌ́WỌ́ ÀWỌN ỌMỌ ẸGBẸ́ ÒKÙNKÙN O – ÀWỌN ARÁ AKWA IBOM

    0 shares
    Share 0 Tweet 0

Connect with us

Newsletter

Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE

Category

Site Links

  • Register
  • Log in
  • Entries feed
  • Comments feed
  • WordPress.org

About Us

We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.

  • About
  • Advertise
  • Careers
  • Contact

© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group

Welcome Back!

Sign In with Facebook
Sign In with Google
Sign In with Linked In
OR

Login to your account below

Forgotten Password? Sign Up

Create New Account!

Sign Up with Facebook
Sign Up with Google
Sign Up with Linked In
OR

Fill the forms below to register

All fields are required. Log In

Retrieve your password

Please enter your username or email address to reset your password.

Log In