ỌWỌ́ TẸ ÀWỌN MÁRÙN-ÚN TÍ WỌ́N TA ỌMỌ ỌWỌ́.
Àwọn márùn-ún ló ti wà ní agodo àwọn àwọn ọlọ́pàá báyìí lórí ẹ̀sùn pé wọ́n ta ọmọ ìkókó, ọmọ ọ̀sẹ̀ ...
Àwọn márùn-ún ló ti wà ní agodo àwọn àwọn ọlọ́pàá báyìí lórí ẹ̀sùn pé wọ́n ta ọmọ ìkókó, ọmọ ọ̀sẹ̀ ...
Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti ṣe ìlérí láti ṣe ìwádìí ìjìnlẹ̀ lórí ikú arábìnrin Folajimi Akinbobola tó kú toyúntoyún. Ẹ̀sùn tí ...
Olajobi Taiwo ti wà ní àhámọ́ àwọn ọlọ́pàá fún ẹ̀sùn ìfipábánilò. Ọmọ ọdún mọ́kàndínlógún ni Olajobi nígbà tí ọmọbìnrin náà ...
Nuru Isah; ẹni àádọ́ta ọdún ti wà ní àhámọ́ àwọn ọlọ́pàá báyìí látàrí pé ó lu iyàwó rẹ̀ kejì; Wasila ...
Àwọn ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ogun ti bọ́ sóde láti wá awakọ̀ kan tó gbá àwọn ọmọ́débìnrin méjì tí wọ́n ń ti ...
Ìbánújẹ́ ńlá ló wọlé bá àwọn ẹbí Sunday Jimoh lálejò ní ọjọ́ kejìlélógún, oṣù Èbìbí yìí nígbà tí Sunday kó ...
Oko ẹ̀gẹ́ tó tó mílíọ̀nù mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n náírà ni àwọn kan tí wọ́n fura sí pé wọ́n jẹ́ darandaran dáná sun ...
Àwọn afurasí méjì kan tí wọ́n máa ń fi ọkọ̀ ṣe ‘one-chance’ ní Abuja lọ́wọ́ tẹ̀. Àwọn èrò pé pitimu ...
Ọlọ́pàá kan ni ó ṣàdédé yìnbọn pa ara rẹ̀ ní àgọ́ ọlọ́pàá nasarawa. Ọjọ́ kẹrin, oṣù Ebìbí yìí ni ìṣẹ̀lẹ̀ ...
Pásítọ̀ ìjọ ìràpadà, The Redeemed christain Church of God; pásítọ̀ Enoch Adeboye sọ̀rọ̀ lórí bí àwọn àjọ ẹlẹ́sìn kan tí ...
Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE
We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group