KÌÍ DÙN KÓ PẸ́, ÀSÌKÒ MERANDA GẸ́GẸ́ BÍI AGBẸNUSỌ ILÉ ÌGBÌMỌ̀ AṢÒFIN ÈKÓ TẸNU BEPO.
Lẹ́yìn gbogbo ìpàdé àti ìfikùnlukùn tó wáyé lórí fàǹfà tó wáyé nílé ìgbìmọ̀ aṣofin, àwọn àgbààgbà ẹgbẹ́ òṣèlú APC àti ...