ẸGBẸ́ ÒṢÈLÚ ADC ṢETÁN ÀTI YẸ ÀGA MỌ́ TINUBU LỌ́DÚN 2027.
Àwọn àgbà olóṣèlú ti kóra jọ darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú ADC pẹ̀lú èròǹgbà àti gba ipò ààrẹ orílẹ̀-ède yìí kúrò ...
Àwọn àgbà olóṣèlú ti kóra jọ darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú ADC pẹ̀lú èròǹgbà àti gba ipò ààrẹ orílẹ̀-ède yìí kúrò ...
Ojora ti ìlú Ijora; Ọba AbdulFatai Oyegbemi ti rọ àwọn olóyè mẹ́fà lóyè nítorí pé wọ́n lọ sí ibi ìpolongo ...
Ó lé ní ọgọ́rùn-ún àwọn agbésùnmọ̀mí tí wọ́n jẹ́ ọmọlẹ́yìn Bello Turji tó dágbére fáyé nígbà tí àwọn ẹ̀ṣọ́ aláàbò ...
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti ṣe ìpàdé ìdákọ̀kọ̀ pẹ̀lú Gómìnà ìpínlẹ̀ Rivers tí ó júwe ilé fún; Siminalayi Fubara àti ...
Òṣèré tíátà ilẹ̀ wa Bukky Raji tí orúkọ ìtàgé rẹ̀ ń jẹ́ Aminatu papapa ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí gbogbo ọmọ ...
Àwọn arìnrìnàjò há sí ojú ònà lónìí nígbà tí ọkọ̀ àjàgbé agbépo kan ṣàdédé gbaná lójú ọ̀nà márosẹ̀ Èkó sí ...
Ìṣẹ̀lẹ̀ omiyalé ní ìpínlẹ̀ Niger ti bá ọ̀nà mìíràn yọ báyìí, ó ti lé ní ọgọ́rùn-ún òkú èèyàn tí wọ́n ...
Gbọ̀gán ìdánwò ilé ìwé girama ìjọba tó wà ní Namnai ní ìjọba ìbílẹ̀ Gassol ní ìpínlẹ̀ Taraba ti wó lé ...
Ààrẹ orílẹ̀-ède wa Nàìjíríà; Aṣíwájú Bola Ahmed Tinubu ti sọ̀rọ̀ nípa ipò tí orílẹ̀-ède Nàìjíríà wà báyìí àti àlàkalẹ̀ ọjọ́ ...
Orílẹ̀-ède Saudi ti kéde pé àwọn ti rí òṣùpá titun tó ṣe àmì ìbẹ̀rẹ̀ oṣù ọdún iléyá. Ọ̀la, ọjọ́ kejìdínlógún, ...
© 2024 -2026 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
We use cookies to improve your experience on our site. By using our site, you consent to cookies.
Manage your cookie preferences below:
Essential cookies enable basic functions and are necessary for the proper function of the website.
These cookies are needed for adding comments on this website.
These cookies are used for managing login functionality on this website.
Statistics cookies collect information anonymously. This information helps us understand how visitors use our website.
Google Analytics is a powerful tool that tracks and analyzes website traffic for informed marketing decisions.
Service URL: policies.google.com (opens in a new window)
Marketing cookies are used to follow visitors to websites. The intention is to show ads that are relevant and engaging to the individual user.
A video-sharing platform for users to upload, view, and share videos across various genres and topics.
Service URL: www.youtube.com (opens in a new window)
© 2024 -2026 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group