Ìròyìn Jákèjádò.
https://www.facebook.com/share/v/15sRp7tyVW/
Sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ ni Kemi lórí ìtàkùn ayélujára ṣaájú ikú bàbá rẹ̀. Lẹ́yìn tí bàbá rẹ̀; Dọ́kítà Omololu Olunloyo kú tán ni ...
Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti ṣe ìlérí láti ṣe ìwádìí ìjìnlẹ̀ lórí ikú arábìnrin Folajimi Akinbobola tó kú toyúntoyún. Ẹ̀sùn tí ...
Àjọ àwọn agbẹjọ́rò àti adájọ́ ilẹ̀ yìí NBA ti dá sí ọ̀rọ̀ tó ń jà ràìràìn lórí ìkànnì ayélujára nípa ...
Arábìnrin Kemi Akinbobola ti kú pẹ̀lú oyún nínú látàrí pé kò ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta náírà owó àsan-án-lẹ̀ tí ilé ìwòsàn bèèrè ...
Ìgbìmọ̀ onídàájọ́ ẹlẹ́ni mẹ́ta, tí Onídàájọ́ Wilfred Kpochi jẹ́ alága wọ́n ti kéde gbígbé ìdájọ́ wọn kalẹ̀ kàà lórí ìgbẹ́jọ́ ...
Ìjàm̀bá ọkọ̀ mẹ́ta ló ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ Àìkú,ọjọ́ ọdún ìtunu ààwẹ̀. Ọ̀kan ṣẹlẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Kastina, òmírà wáyé ní Ogijo, ...
Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ kan tí ó pe orúkọ ara rẹ̀ ní Femi Adio Wonder ti bá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ lórí àìsàn ìtọ̀ ...
Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE
We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group