Ó TÚN TI SẸ O, ÀWỌN Ẹ̀ṢỌ́ ALÁÀBÒ DSS WỌ̀YÁ ÌJÀ PẸ̀LÚ ÀWỌN ỌMỌ ILÉ ÌGBÌMỌ̀ AṢOFIN ÈKÓ.
Ilé ìgbìmọ̀ aṣofin Èkó gbóná janjan láàrọ̀ yìí, ọ̀rọ̀ di làásìgbò láàrin àwọn ọmọ ilé ìgbimo asofin Èkó àti àwọn ...