ILÉ IṢẸ́ ỌLỌ́PÀÁ TI BẸ̀RẸ̀ ÌWÁDÌÍ ÌJÌNLẸ̀ LÓRÍ MEMUNAT TÍ WỌ́N JÍ GBÉ.
Ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Èkó ti bẹ̀rẹ̀ ìwádìí ìjìnlẹ̀ lórí ọmọ ọdún márùn-ún kan; Memunat AbdulRahman tí ọkùnrin kan jí ...