Ẹ̀RỌ ÌBÁNISỌ̀RỌ̀ NI SUNDAY FẸ́ YỌ NÍNÚ KÀNǸGA TÓ FI KÓ SÍNÚ RẸ̀.
Ìbánújẹ́ ńlá ló wọlé bá àwọn ẹbí Sunday Jimoh lálejò ní ọjọ́ kejìlélógún, oṣù Èbìbí yìí nígbà tí Sunday kó ...
Ìbánújẹ́ ńlá ló wọlé bá àwọn ẹbí Sunday Jimoh lálejò ní ọjọ́ kejìlélógún, oṣù Èbìbí yìí nígbà tí Sunday kó ...
Gẹ́gẹ́ bí Ìròyìn lórí èsì ètò ìdìbò tí alága ètò ìdìbò ipinlẹ̀ Ọ̀ṣun fi léde lórí ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ tó ...
Oko ẹ̀gẹ́ tó tó mílíọ̀nù mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n náírà ni àwọn kan tí wọ́n fura sí pé wọ́n jẹ́ darandaran dáná sun ...
Ọ̀gá Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ké tantan pé kí àwọn èèyàn ipinle Osun má bẹ̀rù àtilọ dìbò lọ́jọ́ àbámẹ́ta, ọjọ́ kejìlélógún, ...
Ẹgbẹ́ òṣèlú PDP fẹ̀sùn kan Ọ̀gá Ọlọ́pàá ilẹ̀ yìí, Káyọ̀dé Ẹgbẹ́tókun pé ó gbìmọ̀pọ̀ Pẹ̀lú ẹgbẹ́ òṣèlú APC láti tẹ̀lé ...
Lórí ohun tí a ń jẹ lẹ́nu tí a ò tíì jẹ tán, Obasa fèsì nínú àtẹ̀jáde kan tó bu ...
Nínú Ìròyìn tó lu jáde ní kàtà àwọn ọmọ ẹgbẹ́ APC kan, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, àwọn kan ti ń kábàámọ̀ ...
Àwọn Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ògùn fi ìwé ìwáni síta pé àwọn ń wá ọmọkùnrin tí orúkọ rẹ̀ n jẹ́ HABEEB ỌLÁLỌMÍ ...
Ṣèbí oníkálukú ń ṣe tirẹ̀ lọ́jà lọ́jọ̀ náà ni, àfi gbòlà tí iná sẹ́yọ, iná ọmọ ọ̀rara, kíá ló ti ...
Ilé ìgbìmọ̀ aṣofin Èkó gbóná janjan láàrọ̀ yìí, ọ̀rọ̀ di làásìgbò láàrin àwọn ọmọ ilé ìgbimo asofin Èkó àti àwọn ...
Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE
We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group