Abdullai Ganduje; ẹni tó jẹ́ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC sọ̀rọ̀ níbi ìgbaniwọlé Gómìnà ìpínlẹ̀ Delta àti àwọn ẹmẹ̀wàá rẹ̀ tó...
Read moreDetailsÀwọn ará abulé Kwaple ní ìjọba ìbílẹ̀ Chibok ìpínlẹ̀ Borno pé jọ láti sin òkú àwọn èèyàn tí àwọn agbésùnmọ̀mí...
Read moreDetailsAlága ìjọba ìbílẹ̀ Hong ní ìpínlẹ̀ Adamawa; Usman Wa’anganda bá àwọn akọ̀ròyìn sọ̀rọ̀ lórí àwọn ìkọlù tó ti wáyé ní...
Read moreDetailsNatasha Akpoti-Uduaghan; ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ilẹ̀ yìí ti kọ lẹ́tà ìtọrọ àforíjì sí olórí ilé ìgbìmọ̀ àṣòfin ilẹ̀...
Read moreDetailsỌjọ́ tí àwọn èèyàn ò le gbàgbé bọ̀rọ̀ ni òní jẹ́ ní Agege látàrí ìjàmbá tó wáyé láàárọ̀ yìí. Ọkọ̀...
Read moreDetailsỌwọ́ àwọn ọlọ́pàá ti tẹ àwọn mẹ́jọ kan tí wọ́n pa ọmọ ọdún mẹ́fà kan nípakúpa. Abúlé Bura-Bunga ní agbègbè...
Read moreDetailsGómìnà ìpínlẹ̀ Gombe; Muhamadu Inuwa Yahaya ti ṣe ìlérí mílíọ̀nù méjì náírà fún ọ̀kọ̀ọ̀kan ẹbí àwọn èèyàn tí ọkọ̀ tẹ̀...
Read moreDetailsGọ́mìnà ìpínlẹ̀ Delta; Sheriff Oborevwori ti kéde ìṣípòpadà rẹ̀ láti jíjẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP sí ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú APC....
Read moreDetailsÌjà burúkú kan bẹ́ sílẹ̀ láàrin Olamide àti ìyàwó rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ogun, irin tó gbé sókè pé kó fi...
Read moreDetailshttps://www.facebook.com/share/v/15pjSjpKZz/
Read moreDetailsLorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE
We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group