Ẹ̀RỌ LỌ ÒṢÌṢẸ́ ILÉ IṢẸ́ KÚNNÁ NÍ ÌPÍNLẸ̀ OGUN.
Òṣìṣẹ́ ilé iṣẹ́ kan tó wà ní ìpínlẹ̀ Ogun ti jẹ́ ìpè Elédùà lẹ́yìn tí ẹ̀rọ gbé e hánu tó ...
Òṣìṣẹ́ ilé iṣẹ́ kan tó wà ní ìpínlẹ̀ Ogun ti jẹ́ ìpè Elédùà lẹ́yìn tí ẹ̀rọ gbé e hánu tó ...
Orílẹ̀-ède Saudi ti kéde pé àwọn ti rí òṣùpá titun tó ṣe àmì ìbẹ̀rẹ̀ oṣù ọdún iléyá. Ọ̀la, ọjọ́ kejìdínlógún, ...
Ilé ẹjọ́ gíga ìjọba tó fìkàlẹ̀ sí Kaduna ti pàṣẹ kí Gómìnà ìpínlẹ̀ Kaduna tẹ́lẹ̀rí; Nasir El-Rufai àti àwọn márùn-ún ...
Gómìnà ìpínlẹ̀ Akwa Ibom; Umo Eno ti pàṣẹ fún gbogbo àwọn kọmíṣọ́nà rẹ̀ pé kí wọn ó tẹ̀lé òun kálọ ...
Ọmọ odún mẹ́rìnlá kan tí a kò ní àǹfààní àtidárúkọ rẹ̀ ti sá àsálà fún ẹ̀mí rẹ̀ kúrò nílé ọkọ ...
Hamdiyyah Sharif; ọmọbìnrin tó ké sí gómìnà ìpínlẹ̀ Sokoto pé kí ó wá nǹkan ṣe sí ọ̀rọ̀ àwọn agbésùnmọ̀mí ti ...
Gómìnà ìpínlẹ̀ Borno; Babangana Zulum ti sọ gudugbẹ ọ̀rọ̀ lónìí nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò tó ṣe pẹ̀lú àwọn akọ̀ròyìn News central. Ó ...
Àwọn kan tí wọ́n fura sí pé wọ́n jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn ni wọ́n ti ṣá arákùnrin kan tí wọ́n ...
Ilé iṣẹ́ ológun ilẹ̀ yìí, ẹ̀ka àwọn jagunjagun ojú òfurufú ti kéde pé àwọn ti pa ọlọ́wọ́ ọ̀tún Bello Turji ...
Àwọn márùn-ún ló ti wà ní agodo àwọn àwọn ọlọ́pàá báyìí lórí ẹ̀sùn pé wọ́n ta ọmọ ìkókó, ọmọ ọ̀sẹ̀ ...
Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE
We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group