ÀÀRẸ BOLA AHMED TINUBU YÓÒ ṢE ÌWÚRE ỌJỌ́ ÌBÍ RẸ̀ LÓNÌÍ.
Ààrẹ orile-ede wa Naijiria; Bola Ahmed Tinubu yóò pé ọmọ ọdún mẹ́tàléláàdọ́rin ní ọ̀la ọjọ́ àbámẹ́ta. Adúrà ọjọ́ ìbí yóò ...
Ààrẹ orile-ede wa Naijiria; Bola Ahmed Tinubu yóò pé ọmọ ọdún mẹ́tàléláàdọ́rin ní ọ̀la ọjọ́ àbámẹ́ta. Adúrà ọjọ́ ìbí yóò ...
Kò sí ìgbà tí àwọn akọ̀ròyìn wa ò kúkú ní tẹ̀ ẹ́ pa sí ìpínlẹ̀ Rivers títí oṣù mẹ́fà náà ...
Adẹ́rìnínpòṣónú nnì; Ganiyu Kehinde tí àwọn èèyàn mọ̀ sí Ìjọba Lande tún bá ọ̀nà mìíràn yọ lórí bí Baba Tee ...
Wàhálà burúkú kan tún ti bẹ́ sílẹ̀ ní àgbègbè Ifọ́n-òròlú àti Ìlobùú níbi tí káńsẹ́lọ̀ kan ti pàdánù ẹ̀mí rẹ̀, ...
Ọkọ̀ àjàgbé kan tó gbé afẹ́fẹ́ tí ọkọ̀ le mú sàgbára CNG ló pàdánù ìjánu rẹ̀ ní ìtòsí afárá Karu ...
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti kéde ìpínlẹ̀ Rivers ní ìpínlẹ̀ pàjáwìrì lọ́jọ́ Ìṣẹ́gun. Oṣù mẹ́fà ni ààrẹ wí pé kí ...
Olùdíje sípò Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó lábẹ́ áṣíà ẹgbẹ́ òṣèlú PDP nínú ètò ìdìbò tó kọjá lọ yìí ti padà sínú ...
Timileyin Ajayi fojú ba ilé-ẹjọ́ giga Lafia lónìí, àwọn ẹlẹrìí mẹ́ta ni awon agbẹjọ́rò olùpẹjọ́ kó wá láti tako òun ...
Ẹgbẹ́ òṣèlú APC ẹ̀ka ìpínlẹ̀ Ọ̀șun ti kojú ìșòro ńlá tó sì ń fa kò-bà-ò-le lágbo wọn. Ọ̀rọ̀ yìí kò ...
Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE
We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group