Ẹ̀RỌ LỌ ÒṢÌṢẸ́ ILÉ IṢẸ́ KÚNNÁ NÍ ÌPÍNLẸ̀ OGUN.
Òṣìṣẹ́ ilé iṣẹ́ kan tó wà ní ìpínlẹ̀ Ogun ti jẹ́ ìpè Elédùà lẹ́yìn tí ẹ̀rọ gbé e hánu tó ...
Òṣìṣẹ́ ilé iṣẹ́ kan tó wà ní ìpínlẹ̀ Ogun ti jẹ́ ìpè Elédùà lẹ́yìn tí ẹ̀rọ gbé e hánu tó ...
Ilé ẹjọ́ gíga ìjọba tó fìkàlẹ̀ sí Kaduna ti pàṣẹ kí Gómìnà ìpínlẹ̀ Kaduna tẹ́lẹ̀rí; Nasir El-Rufai àti àwọn márùn-ún ...
Gómìnà ìpínlẹ̀ Akwa Ibom; Umo Eno ti pàṣẹ fún gbogbo àwọn kọmíṣọ́nà rẹ̀ pé kí wọn ó tẹ̀lé òun kálọ ...
Ọmọ odún mẹ́rìnlá kan tí a kò ní àǹfààní àtidárúkọ rẹ̀ ti sá àsálà fún ẹ̀mí rẹ̀ kúrò nílé ọkọ ...
Àwọn kan tí wọ́n fura sí pé wọ́n jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn ni wọ́n ti ṣá arákùnrin kan tí wọ́n ...
Àwọn márùn-ún ló ti wà ní agodo àwọn àwọn ọlọ́pàá báyìí lórí ẹ̀sùn pé wọ́n ta ọmọ ìkókó, ọmọ ọ̀sẹ̀ ...
Àjọ ẹ̀ṣọ́ aáàbò Onelga Security tó wà ní ìpínlẹ̀ Rivers ti ṣe ìkìlọ̀ fún gbogbo àwọn adáhunṣe pé kí wọn ...
Ilé ẹjọ́ gíga ìpínlẹ̀ Èkìtì ti dájọ́ ikú fún David Isaiah fún ẹ̀sùn ìpànìyàn. Ẹni ọdún mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n ni David, ẹ̀sùn ...
Alága ìjọba ìbílẹ̀ Hong ní ìpínlẹ̀ Adamawa; Usman Wa’anganda bá àwọn akọ̀ròyìn sọ̀rọ̀ lórí àwọn ìkọlù tó ti wáyé ní ...
Natasha Akpoti-Uduaghan; ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ilẹ̀ yìí ti kọ lẹ́tà ìtọrọ àforíjì sí olórí ilé ìgbìmọ̀ àṣòfin ilẹ̀ ...
Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE
We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group