GBỌ̀GÁN ÌDÁNWÓ WÓ PA ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ TARABA.
Gbọ̀gán ìdánwò ilé ìwé girama ìjọba tó wà ní Namnai ní ìjọba ìbílẹ̀ Gassol ní ìpínlẹ̀ Taraba ti wó lé ...
Gbọ̀gán ìdánwò ilé ìwé girama ìjọba tó wà ní Namnai ní ìjọba ìbílẹ̀ Gassol ní ìpínlẹ̀ Taraba ti wó lé ...
Ààrẹ orílẹ̀-ède wa Nàìjíríà; Aṣíwájú Bola Ahmed Tinubu ti sọ̀rọ̀ nípa ipò tí orílẹ̀-ède Nàìjíríà wà báyìí àti àlàkalẹ̀ ọjọ́ ...
Orílẹ̀-ède Saudi ti kéde pé àwọn ti rí òṣùpá titun tó ṣe àmì ìbẹ̀rẹ̀ oṣù ọdún iléyá. Ọ̀la, ọjọ́ kejìdínlógún, ...
Gómìnà ìpínlẹ̀ Akwa Ibom; Umo Eno ti pàṣẹ fún gbogbo àwọn kọmíṣọ́nà rẹ̀ pé kí wọn ó tẹ̀lé òun kálọ ...
Arákùnrin kan tí wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní Udochi Amala ti dáná sun ìyàwó àti ọmọ rẹ̀ nítorí pé ó ...
Níbi ibùdó àwọn ọlọ́pàá tó wà ní Isuofia ní ìjọba ìbílẹ̀ Aguata ni ìkọlù náà ti wáyé. Alẹ́ àná Ọjọ́bọ, ...
Àjọ ẹ̀ṣọ́ aáàbò Onelga Security tó wà ní ìpínlẹ̀ Rivers ti ṣe ìkìlọ̀ fún gbogbo àwọn adáhunṣe pé kí wọn ...
Ilé ìwé gíga Babcock tó wà ní Ilishan ti fèsì sí ọ̀rọ̀ Oladipupo Sijuola ọmọ arábìnrin Fijabi Omotayo tó pòórá ...
Ilé ẹjọ́ gíga ìpínlẹ̀ Èkìtì ti dájọ́ ikú fún David Isaiah fún ẹ̀sùn ìpànìyàn. Ẹni ọdún mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n ni David, ẹ̀sùn ...
Arábìnrin Fijabi Oyindamola Omotayo ti ké gbàjarè síta lórí ọmọ rẹ̀ tó di àwátì lẹ́yìn tó gbé e lọ sí ...
Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE
We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group