ÌJÀMBÁ INÁ ORÍ AFÁRÁ Ọ̀TẸ́DỌLÁ GBA Ẹ̀MÍ ÀWỌN TỌKỌ-TAYÀ TUNTUN
Ọ̀sẹ̀ kẹta rèé tí tọkọ-tayà ṣègbéyàwó, tí wọ́n filé pọn ọtí, fi ọ̀nà rokà; tí inú ẹbí, ará àti ọ̀rẹ́ ...
Ọ̀sẹ̀ kẹta rèé tí tọkọ-tayà ṣègbéyàwó, tí wọ́n filé pọn ọtí, fi ọ̀nà rokà; tí inú ẹbí, ará àti ọ̀rẹ́ ...
Olajobi Taiwo ti wà ní àhámọ́ àwọn ọlọ́pàá fún ẹ̀sùn ìfipábánilò. Ọmọ ọdún mọ́kàndínlógún ni Olajobi nígbà tí ọmọbìnrin náà ...
Ọ̀gá ọlọ́pàá ti ìpínlẹ̀ AKWA IBOM ní ọwọ́ ti tẹ pásítọ̀ ìjọ REDEEMED CHRISTAIN CHURCH OF GOD (RCCG), ọmọ ọdún ...
Ọ̀kan nínú àwọn Ògúná gbòǹgbò tíí dátọ́ lẹ́nu ìgbín inú ẹgbẹ́ PDP; Olóyè Bọ̀dé George ti gbéná wo ojú Jandor ...
ỌKÙNRIN MỌ́KÀNLÉLÓGÚN LÓ BÁ ÌYÀWÓ MI LÒ PỌ̀- ÌJỌBA LANDE Ganiyu Morufu, adẹ́rìn-ínpòṣónú nnì ti ju bọ́ḿbù titun sílẹ̀ nípa ...
Ẹgbẹ́ òṣèlú APC ti sọ̀rọ̀ lórí yíyapa tí El-Rufai yapa kúrò nínú ẹgbẹ́ òṣèlú náà lọ sínú ẹgbẹ́ òṣèlú SDP. ...
Àjọ SERAP ( SOCIO-ECONOMIC RIGHTS AND ACCOUNTABILITY PROJECT) ti ké tantan sí Sẹnetọ GOODSWILL AKPABIO pé ní kíákíá, mọna wáà! ...
Ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá yìí ni Kọmíṣánnà fùn ètò ẹ̀kọ́ ní ìpínẹ̀ Èkó, Alàgbà JAMIU ALLI-BALOGUN ní ó di èèwọ̀ ...
Àwọn òṣìṣẹ́ iná mọ̀nàmọ́ná IKEJA ELECTRICITY DISTRIBUTION COMPANY ṣàgbákò lánàá látàrí bí wọ́n ti kúndùn láti máa sọ àwọn ènìyàn ...
Èmi ò- jù- ọ́, ìwọ ò- jù- mí , ibí ni mo fẹ́ jókòó, èmi ò fẹ́ ibí, jókòó síbẹ̀, ...
Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE
We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group