ÀWỌN OLÓGUN TI ṢEKÚ PA ỌLỌ́WỌ́ Ọ̀TÚN BELLO TURJI NÍ SOKOTO.
Ilé iṣẹ́ ológun ilẹ̀ yìí, ẹ̀ka àwọn jagunjagun ojú òfurufú ti kéde pé àwọn ti pa ọlọ́wọ́ ọ̀tún Bello Turji ...
Ilé iṣẹ́ ológun ilẹ̀ yìí, ẹ̀ka àwọn jagunjagun ojú òfurufú ti kéde pé àwọn ti pa ọlọ́wọ́ ọ̀tún Bello Turji ...
Àwọn márùn-ún ló ti wà ní agodo àwọn àwọn ọlọ́pàá báyìí lórí ẹ̀sùn pé wọ́n ta ọmọ ìkókó, ọmọ ọ̀sẹ̀ ...
Níbi ibùdó àwọn ọlọ́pàá tó wà ní Isuofia ní ìjọba ìbílẹ̀ Aguata ni ìkọlù náà ti wáyé. Alẹ́ àná Ọjọ́bọ, ...
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú NNPP méjì tí wọ́n jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣojúṣòfin ló ti digbádagbọ̀n wọn kúrò nínú ẹgbẹ́ ...
Ìròyìn tó gba àwọn ojú ìwé ìròyìn kan láàárọ̀ yìí ni ikú arábìnrin Agbakaizu; ẹni tó jẹ́ akàròyìn ní ilé ...
Àjọ ẹ̀ṣọ́ aáàbò Onelga Security tó wà ní ìpínlẹ̀ Rivers ti ṣe ìkìlọ̀ fún gbogbo àwọn adáhunṣe pé kí wọn ...
Ilé ìwé gíga Babcock tó wà ní Ilishan ti fèsì sí ọ̀rọ̀ Oladipupo Sijuola ọmọ arábìnrin Fijabi Omotayo tó pòórá ...
Ilé ẹjọ́ gíga ìpínlẹ̀ Èkìtì ti dájọ́ ikú fún David Isaiah fún ẹ̀sùn ìpànìyàn. Ẹni ọdún mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n ni David, ẹ̀sùn ...
Ní agbègbè Ajowa Akoko ní ìpínlẹ̀ Ondo, nǹkan ò fara rọ fún arákùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Monday ...
Arábìnrin Fijabi Oyindamola Omotayo ti ké gbàjarè síta lórí ọmọ rẹ̀ tó di àwátì lẹ́yìn tó gbé e lọ sí ...
Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE
We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group