SAUDI TI KÉDE ỌJỌ́ KẸFÀ, OṢÙ IGBE NÍ ỌJỌ́ ỌDÚN ILÉYÁ.
Orílẹ̀-ède Saudi ti kéde pé àwọn ti rí òṣùpá titun tó ṣe àmì ìbẹ̀rẹ̀ oṣù ọdún iléyá. Ọ̀la, ọjọ́ kejìdínlógún, ...
Orílẹ̀-ède Saudi ti kéde pé àwọn ti rí òṣùpá titun tó ṣe àmì ìbẹ̀rẹ̀ oṣù ọdún iléyá. Ọ̀la, ọjọ́ kejìdínlógún, ...
Gómìnà ìpínlẹ̀ Akwa Ibom; Umo Eno ti pàṣẹ fún gbogbo àwọn kọmíṣọ́nà rẹ̀ pé kí wọn ó tẹ̀lé òun kálọ ...
Natasha Akpoti-Uduaghan; ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ilẹ̀ yìí ti kọ lẹ́tà ìtọrọ àforíjì sí olórí ilé ìgbìmọ̀ àṣòfin ilẹ̀ ...
Gómìnà ìpínlẹ̀ Gombe; Muhamadu Inuwa Yahaya ti ṣe ìlérí mílíọ̀nù méjì náírà fún ọ̀kọ̀ọ̀kan ẹbí àwọn èèyàn tí ọkọ̀ tẹ̀ ...
Gọ́mìnà ìpínlẹ̀ Delta; Sheriff Oborevwori ti kéde ìṣípòpadà rẹ̀ láti jíjẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP sí ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú APC. ...
Ìjà burúkú kan bẹ́ sílẹ̀ láàrin Olamide àti ìyàwó rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ogun, irin tó gbé sókè pé kó fi ...
Ilé ẹjọ́ tó fìkàlẹ̀ sí ìpínlẹ̀ Ekiti ti pàṣẹ kí Joy Ikoja ó lọ rọ́kún lọ́gbà ẹ̀wọ̀n lórí ẹ̀sùn pé ...
Orin tí Eedris AbdulKareem kọ ti dá awuyewuye sílẹ̀ láárin àjọ NBC, Eedris Abdulkareem fúnra rẹ̀, Ọ̀jọ̀gbọ́n Wole Soyinka àti ...
Ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti fagi lé ẹjọ́ tí wọ́n ń bá Olorì Ọ̀ọ̀ni tẹ́lẹ̀; Naomi Silekunola àti Oriyomi Hamzat ṣe ...
Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE
We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group