Ìròyìn Jákèjádò.
https://www.facebook.com/share/v/15sRp7tyVW/
Gómìnà ìpínlẹ̀ Kaduna tẹ́lẹ̀rí; Nasir El-Rufai ti fèsì sí awuyewuye tó ń lọ lórí ìtàkùn ayélujára pé òun bá ọ̀rọ̀ ...
Aláàfin Ọ̀yọ́; Ọba Abimbola Akeem Owoade ti fìdí ẹ̀ múlẹ̀ pé kò dìgbà tí ilé ọba bá jó ká tó ...
Arábìnrin Kemi Akinbobola ti kú pẹ̀lú oyún nínú látàrí pé kò ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta náírà owó àsan-án-lẹ̀ tí ilé ìwòsàn bèèrè ...
Bí ìgbà tí èèyàn ń lọ kó adìyẹ lóko ni àwọn ajínigbé ṣe ń kó àwọn èèyàn ní ìpínlẹ̀ Delta ...
Ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ ti ìpínlẹ̀ Èkó ṣe ìkìlọ̀ àti ìránnilétí fún àwọn ilé ìwé gbogbo pé wọn kò gbọdọ̀ na ...
Lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọjọ́ àti ọ̀sẹ̀ tó kún fún rògbòdìyàn àti ẹ̀șíkanrín wàhálà òṣèlú ní ilé ìgbìmọ̀ Așòfin Èkó, àwọn àgbààgbà ...
Ẹ gbọ́ kí la mí ṣe lónìí o? Ìyàwó la mí gbé o! Ó kàn jẹ́ pé orílẹ̀-èdè Tanzania ni ...
Mo kí gbogbo ènìyàn tó wà nínú ọkọ̀ ojú omi Ìwé Iroyin Yorùbá. Nípa oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run, ọkọ̀ ojú omi ìwé ...
Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE
We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group