• About
  • Advertise
  • Careers
  • Contact
Wednesday, May 28, 2025
  • Login
  • Register
No Result
View All Result
NEWSLETTER
ÌWÉ ÌRÒYÌN YORÙBÁ
  • Ilé Wa
  • Ìròyìn
    • All
    • ijamba oko
    • Ìròyìn Agbègbè
    • Ọ̀rọ̀ Ààbò
    • Ọ̀rọ̀ ìdílé
    • Ọrọ̀-Ajé
    • Òṣèlú
    ÌYÁ ÀTI ÌYÁ ÌYÁ TA ỌMỌ ỌJỌ́ MÉJÌ.

    Ẹ̀RỌ LỌ ÒṢÌṢẸ́ ILÉ IṢẸ́ KÚNNÁ NÍ ÌPÍNLẸ̀ OGUN.

    SAUDI TI KÉDE ỌJỌ́ KẸFÀ, OṢÙ IGBE NÍ ỌJỌ́ ỌDÚN ILÉYÁ.

    ÀBẸ̀WÒ MI SÍ ILÉ MUHAMMADU BUHARI KÒ LỌ́WỌ́ ÒṢÈLÚ NÍNÚ – EL RUFAI

    ILÉ ẸJỌ́ PÀṢẸ KÍ EL-RUFAI Ó SAN Ẹ̀Ẹ́DẸ́GBẸ̀RÚN MÍLÍỌ́NÙ NÁÍRÀ OWÓ ÌTANRÀN.

    Ẹ TẸ̀LÉ MI KÁLỌ INÚ ẸGBẸ́ ÒṢÈLÚ APC TÀBÍ KÍ Ẹ KỌ̀WÉ FIPÒ YÍN SÍLẸ̀ – GÓMÌNÀ ÌPÍNLẸ̀ AKWA IBOM SÍ ÀWỌN KỌMÍṢỌ́NÀ RẸ̀.

    ỌMỌ ỌDÚN MẸ́RÌNLÁ SÁ KÚRÒ NÍLÉ ỌKỌ RẸ̀, ỌKỌ RẸ̀ FI SHARIA GBÉ E.

    ÀWỌN OLỌṢÈLÚ LÓ Ń FÚN ÀWỌN AGBÉSÙNMỌ̀MÍ LỌ́WỌ́ – GÓMÌNÀ ÌPÍNLẸ̀ BORNO.

    WỌ́N TI RÍ HAMDIYYAH O!

    HAMDIYYAH SHARIF TI DI ÀWÁTÌ.

    ÌJÀMBÁ INÁ LỌ́TÙN-ÚN LÓSÌ.

    ỌKỌ DÁNÁ SUN ÌYÀWÓ ÀTI ÀWỌN ỌMỌ RẸ̀ MẸ́TA NÍ ABIA.

    • Ìròyìn Agbègbè
    • Ọ̀rọ̀ Ààbò
    • Ọrọ̀-Ajé
    • Òṣèlú
  • Ìròyìn Tó Gbòde
  • Eré ìdárayá
  • Ìdánilárayá
    • All
    • Fiimu ati Nollywood
    • Orin

    ÌGBÉYÀWÓ PRISCILLA MÌLÚ TÌTÌ.

    ÌGBÉYÀWÓ PRISCILLA MÌLÚ TÌTÌ.

    LÁÀRIN TINUBU, EEDRIS ABDULKAREEM ÀTI WOLE SOYINKA.

    Ìròyìn Jákèjádò.

    Ìròyìn Jákèjádò.

    MO TA ILÉ ÀTI Ọ̀NÀ MI LÓRÍ ÀÌSÀN ÌTỌ̀ ṢÚGÀ – AGBÓHÙNSÁFẸ́FẸ́.

    TUFACE RA ÀWỌN AṢỌ TITUN FÚN ÌFẸ́ RẸ̀ TITUN; NATASHA

    ỌKÙNRIN MỌ́KÀNLÉLÓGÚN LÓ BÁ ÌYÀWÓ MI LÒ PỌ̀- ÌJỌBA LANDE

    MI Ò NÍ LE BÁ BABA TEE ṢIṢẸ́ PỌ̀ – ÌJỌBA LANDE.

    ÈMI NI ÌYÀWÓ ẸLẸ́Ẹ̀KEJE ỌKỌ MI :

    ÈMI NI ÌYÀWÓ ẸLẸ́Ẹ̀KEJE ỌKỌ MI :

    Ramadan Kareem!

    Ramadan Kareem!

    • Fiimu ati Nollywood
    • Orin
  • Ìgbé-Ayé
    • All
    • Ìlera
    • Ìrìn Àjò
    • Oge Ṣiṣe

    ÀWỌN OLÓGUN TI ṢEKÚ PA ỌLỌ́WỌ́ Ọ̀TÚN BELLO TURJI NÍ SOKOTO.

    ÀWỌN ỌMỌ ẸGBẸ́ ÒKÙNKÙN ṢEKÚ PA BENJAMIN NÍ IKORODU.

    Trending Tags

    • Golden Globes
    • Mr. Robot
    • MotoGP 2017
    • Climate Change
    • Flat Earth
    • Oge Sise
    • Ìlera
    • Ìrìn Àjò
  • Fọ́nrán
  • Àṣà Yorùbá
    • All
    • Àjọ̀dún Yorùbá
    • Ìtàn Yorùbá
    • Oríkì
    ÌYÀWÓ NI OLAMIDE FẸ́ FỌ́ IRIN MỌ́ LÓRÍ TÓ FI BA ỌMỌ RẸ̀, ỌMỌ ỌDÚN KAN.

    ILÉ ẸJỌ́ DÁJỌ́ IKÚ FÚN ỌKÙNRIN TÓ ṢEKÚ PA COMFORT JAMES.

    Àwọn agbébọn

    ÀWỌN AGBÉBỌN ṢE ÌKỌLÙ SÍ ÌPÍNLẸ̀ KWARA.

    ÌGBÉYÀWÓ PRISCILLA MÌLÚ TÌTÌ.

    ÌGBÉYÀWÓ PRISCILLA MÌLÚ TÌTÌ.

    ILÉ ỌBA Ọ̀YỌ́ KÒ JÓ ÀMỌ́ A Ó BU ẸWÀ SÍI – ỌBA OWOADE.

    ALÁÀFIN YAN OSUNTOLA NÍ OLÙBÁDÁMỌ̀RÀN PÀTÀKÌ.

    Àkàgbádùn

    Àkàgbádùn

    Ewì

    Ewì.

    • Àjọ̀dún Yorùbá
    • Ìtàn Yorùbá
    • Oríkì
  • Ààyè Olóòtú

Home Ààyè Olóòtú

MI Ò NÍ LE BÁ BABA TEE ṢIṢẸ́ PỌ̀ – ÌJỌBA LANDE.

Dara bẹ̀ mí lóòótọ́ àmọ́ mi ò le dárí jì í.

by Adeola Olanrewaju
March 23, 2025
in Ààyè Olóòtú, Fiimu ati Nollywood, Ìgbé-Ayé, Ìròyìn, Ìròyìn Agbègbè, Ìròyìn Tó Gbòde, Ọ̀rọ̀ Ààbò, Ọ̀rọ̀ ìdílé
0
ỌKÙNRIN MỌ́KÀNLÉLÓGÚN LÓ BÁ ÌYÀWÓ MI LÒ PỌ̀- ÌJỌBA LANDE
0
SHARES
9
VIEWS
Pín Lórí FacebookPín Lórí ThreadsPín Lórí TwitterPín Lórí Bluesky

Adẹ́rìnínpòṣónú nnì; Ganiyu Kehinde tí àwọn èèyàn mọ̀ sí Ìjọba Lande tún bá ọ̀nà mìíràn yọ lórí bí Baba Tee ṣe ku ìyàwó rẹ̀; Dara bí èlùbọ́ tó sì tún kì í bí ìbọn.
Lande wí pé gbogbo iṣẹ́ tí wọ́n ń pe òun sí tó sì jẹ́ pé wọ́n pe Baba Tee náà sí ni òun kọ̀ àmọ́ òun kò mọ̀ pé wọ́n pe baba Tee sí iṣẹ́ èyí tí àwọn ti pàdé yìí.
Lande ṣe àlàyé pé lọ́jọ́ náà, òun ti dé sí ilé Yemi Elesho, nígbà tí Baba Tee dé ó bẹ̀rẹ̀ sí ní bẹ òun pé kí òun ó má bínú tó sì fẹ́ kúnlẹ̀, Lande wí pé òun kò fẹ́ kó kúnlẹ̀ fún òun nítorí pé ó dàgbà ju òun lọ ni òun ṣe gbé e dìde nínú fọ́nrán náà, ó wí pé ohun tó ṣẹlẹ̀ yàtọ̀ sí ohun tí àwọn èèyàn ń sọ pé òun ń bẹ baba Tee.
Ó tẹ̀ síwájú nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ pé lóòótọ́ ni òun ti ṣe àforíjì fún baba Tee àmọ́ òun kò ní le bá a ṣiṣẹ́ pọ̀ báyìí nítorí pé ọkàn òun kò tíì kúrò níbẹ̀ bóyá lọ́jọ́ iwájú.

Nípa Dara ìyàwó Lande.

Lande wí pé òun kò ní le ṣe àforíjì fún Dara nítorí pé lẹ́yìn tó kúrò nílé òun ló tún ń parọ́ mọ́ òun nínú àwọn ìfọ̀rọwánilẹ́nuwò tó ṣe, ó ní òun mọ̀ọ́nmọ̀ má fèsì ni kí wọ́n má sọ òun lẹ́nu.
Gbogbo ọ̀rọ̀ yìí bẹ̀rẹ̀ nígbà tí Lande fi ẹ̀sùn kan Baba Tee pé ó ń pọnmi lódò ìyàwó òun.
Ọ̀rọ̀ yìí dá yánpọnyánrin sílẹ̀ lórí ìkànnì ayélujára, a mú ìròyìn náà wá fún yín pé ‘ oníkànǹga àjípọn nìyàwó òun. Ó wí pé gbogbo àwọn ọkùnrin òṣèré tíátà ni wọ́n ń mú un balẹ̀, bí o bá kàá léní, èjì, ẹ̀ta, ó ti lé ní ọkùnrin mọ́kànlélógún tó ti pọnmi lódò ìyàwó òun.
Yàtọ̀ sí Baba Tee tí Lande ti dárúkọ tẹ́lẹ̀, ó wí pé àwọn gbajúgbajà òṣèrékùnrin ni wọ́n ti jẹ ìyàwó òun bíi iṣu.
Baba Tee kọ́kọ́ jiyàn pé òun kò bá ìyàwó rẹ̀ sùn pé tó bá dáa lójú kó mú ẹ̀rí jáde tàbí kó fojú ba ilé ẹjọ́ fún ẹ̀sùn ìbanilórúkọjẹ́. Nígbà tó ríi pé ẹ̀rí wà ló yíhùn padà pé òun bá obìnrin náà lò pọ̀ lóòótọ́ àmọ́ òun kò mọ̀ pé ìyàwó rẹ̀ ni, ó ní kí Lande ó má bínú.
Baba Tee kò ṣàì má ṣe àlàyé bí ọ̀rọ̀ náà ṣe jẹ́, ó wí pé lọ́jọ́ náà, MaryGold; ọ̀rẹ́ Dara tó sì tún jẹ́ máníjà Lande ló mú Dara wá sílé òun, wọ́n bèèrè fún ọtí, lẹ́yìn náà ni àwọn ṣe eré mo tó bẹ́ẹ̀ – mi ò tó bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú ọtí àmupara. Nínú eré náà ni MaryGold ti fún òun ní ìbálòpọ̀ ẹnu tó sì wí pé kí òun ó bá Dara lò látẹ̀yìn, ó ní òun mú ọ̀rá ìdáàbò-bò òun sì ṣe é ní fẹ́rẹ́jógí. Baba Tee wí pé òun kò tẹ àtèkanlẹ̀ rárá kódà òun kò damira. Ó wí pé òun kò mọ bí Lande ṣe ní fọ́nrán náà nítorí kò sí ẹlòmíràn níbẹ̀.
Dara tí a fẹ̀sùn kàn náà fèsì o, ó kọ́kọ́ wí pé irọ́ ni gbogbo ọ̀rọ̀ náà pé òun kàn jókòó lé Baba Tee lẹ́sẹ̀ lásán ni òun kò bá a ṣe nǹkan kan. Àmọ́ o, nígbà tí ẹ̀rí jáde pẹ̀lú ẹsẹ̀ méjì digbí nílẹ̀, ó wí pé ó ṣeé ṣe kí Baba Tee ó bá òun sùn kí òun ó má mọ̀.
Ijoba Lande kò gba àlàyé tí Baba Tee ṣe yìí wọlé o, ó wí pé lẹ́yìn tó fún ní fẹ́rẹ́jógí pé ó padà mú un lọ sí ìyẹ̀wù rẹ̀ níbi tó ti tẹ àtèkanlẹ̀. Ó ní ó fara balẹ̀ ki Dara bíi ìbọn ni pé kò kánjú ṣe é rárá.
Lande kò dúró níbẹ̀ o, ó wí pé kìí ṣe Marygold ló ń gbé ìyàwó òun fún ọkùnrin nítorí pé àwọn fọ́nrán mìíràn tí òun ní lọ́wọ́, kò sí Marygold níbẹ̀ fúnra ìyàwó òun ló ń gbé oúnjẹ alẹ́ òun fún olóńgbò jẹ.
Ó wí pé inú òun bàjẹ́ gidi nígbà tí òun wo àwọn fọ́nrán bí wọ́n ṣe ń ku ìyàwó òun bíi aṣọ òfì tí wọ́n ń lọ̀ ọ́ bí ata tí wọ́n ń gbo ó bíi aṣọ tí wọ́n tún ń gún bí iyán. Lande tẹ̀síwájú pé àwọn bọ́tìnì tí òun ò tẹ̀ rí lára ìyàwó òun ni wọ́n ti tẹ̀ bàjẹ́ lára rẹ̀. Inú ìbànújẹ́ yìí lòun wà láti bíi oṣù mẹ́rin tí ìyàwó òun ti lọ. Marygold; Ọ̀rẹ́ Dara tó sì tún jẹ́ máníjà Lande náà ganu sí ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn án yìí, ó wí pé òun kò fẹ́ tú àṣírí Dara ni pé onínàbì gidi tààrà níí ṣe. Marygold wí pé ìwà nàbì yìí náà ló mú kí ọkọ àárọ̀ rẹ̀ ó kọ̀ọ́ sílẹ̀.
Ó gbìyànjú àtifọ ara rẹ̀ mọ́ pé òun kọ́ ló ń mú Dara lọ pàdé àwọn ọkùnrin nílé ìtúra káàkiri.
Dara náà fèsì o, ó wí pé òun kìí ṣe onínàbí pé ìjókòó lásán lòun jókòó lé Baba Tee lẹ́sẹ̀, bóyá ó wá bá òun sùn, òun kò mọ̀. Dara wí pé Marygold ló mú òun mọ Baba Tee nínú oṣù Agẹmọ ọdún tó kọjá, ó mú òun lọ sí ilé Baba Tee lọ́jọ́ náà nítorí fíìmù rẹ̀ tó fẹ́ gbé jáde. Baba Tee kò ní ọtí nílé, Marygold àti dereba Baba Tee jọ lọ ra ọtí wá
Dara wí pé ibi tí òun jókòó sí tó fi lọ náà ló dé bá òun pé òun àti Baba Tee kò tahun síra.
Ní báyìí, Lande wí pé fọ́nrán bíi mẹ́jọ ló wà lọ́wọ́ òun níbi tí wọ́n ti fi okó dábírà fú Dara ìyàwó òun tí òun náà sì ń gbádùn rẹ̀’

Bí gbogbo rẹ̀ ṣe lọ nìyẹn o, Dara ti kúrò nílé Lande, Lande ti tẹ̀ síwájú nínú ìrìn àjò ayé rẹ̀ ó sì ti padà sí ẹnu ìṣẹ́ rẹ̀ àmọ́ ó fi ààké kọ́rí pé òun kò le bá baba Tee ṣiṣẹ́ pọ̀ mọ́.

Facebook Comments Box
Tags: #iweiroyinyorubababatee sagalandenewsonlinenewsupdatenollywood
Adeola Olanrewaju

Adeola Olanrewaju

Next Post
ÌRÓYÌN AYỌ̀ DÉ FÚN ÀWỌN ÈÈYÀN ÌPÍNLẸ̀ RIVERS

Recommended

LÁÀRIN TINUBU, EEDRIS ABDULKAREEM ÀTI WOLE SOYINKA.

LÁÀRIN TINUBU, EEDRIS ABDULKAREEM ÀTI WOLE SOYINKA.

1 month ago
OLÓRÍ ÀWỌN ÒṢÌṢẸ̀ ÌPÍNLẸ̀ RIVERS TI KỌ̀WÉ FIPÒ RẸ̀ SÍLẸ̀.

2 months ago

Popular News

  • ÌYÁ ÀTI ÌYÁ ÌYÁ TA ỌMỌ ỌJỌ́ MÉJÌ.

    Ẹ̀RỌ LỌ ÒṢÌṢẸ́ ILÉ IṢẸ́ KÚNNÁ NÍ ÌPÍNLẸ̀ OGUN.

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • SAUDI TI KÉDE ỌJỌ́ KẸFÀ, OṢÙ IGBE NÍ ỌJỌ́ ỌDÚN ILÉYÁ.

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • ILÉ ẸJỌ́ PÀṢẸ KÍ EL-RUFAI Ó SAN Ẹ̀Ẹ́DẸ́GBẸ̀RÚN MÍLÍỌ́NÙ NÁÍRÀ OWÓ ÌTANRÀN.

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • ỌMỌ ỌDÚN MẸ́RÌNLÁ SÁ KÚRÒ NÍLÉ ỌKỌ RẸ̀, ỌKỌ RẸ̀ FI SHARIA GBÉ E.

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • Ẹ TẸ̀LÉ MI KÁLỌ INÚ ẸGBẸ́ ÒṢÈLÚ APC TÀBÍ KÍ Ẹ KỌ̀WÉ FIPÒ YÍN SÍLẸ̀ – GÓMÌNÀ ÌPÍNLẸ̀ AKWA IBOM SÍ ÀWỌN KỌMÍṢỌ́NÀ RẸ̀.

    0 shares
    Share 0 Tweet 0

Connect with us

Newsletter

Lorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE

Category

Site Links

  • Register
  • Log in
  • Entries feed
  • Comments feed
  • WordPress.org

About Us

We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.

  • About
  • Advertise
  • Careers
  • Contact

© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group

Welcome Back!

Sign In with Facebook
Sign In with Google
Sign In with Linked In
OR

Login to your account below

Forgotten Password? Sign Up

Create New Account!

Sign Up with Facebook
Sign Up with Google
Sign Up with Linked In
OR

Fill the forms below to register

All fields are required. Log In

Retrieve your password

Please enter your username or email address to reset your password.

Log In