Àwọn Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ògùn fi ìwé ìwáni síta pé àwọn ń wá ọmọkùnrin tí orúkọ rẹ̀ n jẹ́ HABEEB ỌLÁLỌMÍ...
Read moreDetailsṢèbí oníkálukú ń ṣe tirẹ̀ lọ́jà lọ́jọ̀ náà ni, àfi gbòlà tí iná sẹ́yọ, iná ọmọ ọ̀rara, kíá ló ti...
Read moreDetailshttps://www.facebook.com/61556729257605/videos/1595960751055827/
Read moreDetailsGbogbo àgbáríjọ àwọn àgbààgbà ilẹ̀ Yorùbá tí a mọ̀ sí “ Congress of Yorùbá Leaders” ti bu ẹnu àtẹ́ àti...
Read moreDetailsỌwọ́ àwọn ẹṣọ́ aláàbò ÀMỌ̀TẸ́KÙN ti Ifọ̀ ní ìpínlẹ̀ Ògùn tẹ àwọn ọ̀bàyéjẹ́ kan tó n fi àwọn ọmọdébìnrin tí...
Read moreDetailsọ̀fin titun fún àwọn oníbàárà ilé ìfowópamọ́ láti ẹnu Ọ̀gá àgbà fún ilé ìfowópamọ́ àgbà ní ilẹ̀ Nàìjíríà; CBN; Alàgbà...
Read moreDetailsIlé ìgbìmọ̀ aṣofin Èkó gbóná janjan láàrọ̀ yìí, ọ̀rọ̀ di làásìgbò láàrin àwọn ọmọ ilé ìgbimo asofin Èkó àti àwọn...
Read moreDetailsNí báyìí, Ìpínlẹ̀ Ọ̀șun tó ti ń tùbà-tùṣẹ tẹ́lẹ̀ ti di ibùdó ẹ̀rù-jẹ̀ẹ̀ fún aráàlú nítorí wàhálà tó Bẹ́ sílẹ̀...
Read moreDetailsÀwọn afurasí méjì kan tí wọ́n máa ń fi ọkọ̀ ṣe ‘one-chance’ ní Abuja lọ́wọ́ tẹ̀. Àwọn èrò pé pitimu...
Read moreDetailsÓ ti lé lọ́dún kan gbáko báyìí ti Ọba Alápetúmodù ti Ìlú Ìpétúmodu ti di àfẹ́kù. Ilẹ̀ Amẹ́ríkà ni Ọba...
Read moreDetailsLorem ipsum dolor sit amet, consectetuer adipiscing elit. Aenean commodo ligula eget dolor.
SUBSCRIBE
We bring you the best Premium WordPress Themes that perfect for news, magazine, personal blog, etc. Check our landing page for details.
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group
© 2024 The Morganable Media Group - Ìwé Ìròyìn Yorùbá is owned by The Morganable Media Group